Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

domingo, 21 de julho de 2019

Presidente subserviente (ààrẹ tó ń pọ́nni)

›
Ẹnu tó ń pọ́nni sì ń fa ìparun. E a boca bajuladora causa ruína. Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário). Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário). Ẹ...

›
Ǹjẹ́ o ti sun ìṣù búrẹ́dì tí a fi ẹran lílọ̀ há láàárín pọ̀  fún ara mi? Já fritou o hambúrguer para mim? Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú...

Bolsonaro diz que cogita nomear o filho como embaixador dos EUA

›
Fún ọmọ rẹ̀ , ọkọ́. Fún ọmọ mi, Iléeṣẹ́ tó ń ṣojú orílẹ̀-èdè kan.  Ṣé o ti lóye, tálákà ? Para o seu filho, enxada. Para o meu filho. emba...

Ore por Bolsonaro

›
  Baba wa tí ḿbẹ l' ọ́run , dá wa nídè kúrò lọ́wọ́ ẹni burúkú yìí.  Pai nosso, que estais  nos céus, livra-nos desse mal.           ...
domingo, 14 de julho de 2019

Crime contra a humanidade

›
Àwọn èèyàn ti ń hùwà ibi séèyàn ẹlẹgbẹ́ wọn. Crimes contra a humanidade. Ação de Bolsonaro na Amazônia poderá ser considerada crime con...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.