Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

domingo, 17 de maio de 2020

Ritual de magia negra

›
Oríṣi agbára òkùnkùn kan ti ọmọlẹ́hìn Bolsonaro tó ń lò ọwọ́ rẹ̀ bí àmi ti ohun ìjà kékeré àti  ìtẹríba fún Sátánì. Um tipo de magia negra...
quarta-feira, 13 de maio de 2020

Reteté

›
  Ijó ti onigbagbọ pẹntikọ́sítà kan tí kò ní ṣàkóso ìgbésẹ̀ ara rẹ̀, ó sì sábà ń ṣẹlẹ̀ nígbà tí ẹ̀mí mímọ́ bá wà nínú rẹ̀. Dança de um cr...
terça-feira, 12 de maio de 2020

Comunidade preta mundial

›
1. Ẹgbẹ́ àwọn ará dúdú tó kárí ayé. Comunidade preta mundial. Àwọn adúláwọ̀ yíká ayé (negros em todo o mundo): àwọn adúláwọ̀ ọmọ Áfírík...
quinta-feira, 30 de abril de 2020

Raça preta

›
Ìran ẹ̀dá èèyàn dúdú. Raça preta.         No livro , "A Origem Africana da Psiquiatria Biológica", o DR Richard King  afirma ...
terça-feira, 28 de abril de 2020

Dicionário yorubá

›
 Ìwé atúmọ̀ èdè yorùbá (dicionário yorubá) Ọ̀wọ́ ọ̀rọ̀ tó wà nínú èdè, àwọn ọ̀rọ̀ tó máa lò, àkójọ ọ̀rọ̀ tí ò ń lò lójoojúmọ́, àwọn àkàn...
segunda-feira, 27 de abril de 2020

Medicamentos de origem africana contra a covid-19: Covid-Organics e Apivirine

›
1. Ààrẹ Orílẹ̀-Èdè Olómìnira ilẹ̀ Madagáskàr fi egbòogi hàn tó ń wo Covid-19 sàn.  O Presidente da República de Madagascar mostra remédio ...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.