Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

segunda-feira, 25 de maio de 2020

Fascismo

›
                                          Ṣé o mọ̀ ohun tí ètò ìjọba aláṣẹ oníkùmọ̀ ni? Você sabe o que é fascismo? Tó o bá fẹ́ ìsọfú...
domingo, 24 de maio de 2020

Cristianismo

›
"Ẹ̀sìn Krístì fi Ísírẹ́lì sílẹ̀ bí ìdílé, ó wá sí Róòmù  gẹ́gẹ́ bí  ẹ̀sìn kan, ó lọ sí Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì gẹ́gẹ́ bí ètò ìṣèlú kan ó sì parí n...
terça-feira, 19 de maio de 2020

Estrada Pan-Africana

›
Òpópónà títẹ́jú tó la àárín àwọn orílẹ̀-èdè Áfríkà kọjá. Estrada Pan-Africana. A Rodovia Transafricana 4 (TAH 4), também conhecida co...

Rodovia Panamericana

›
Òpópónà títẹ́jú tó la àárín àwọn orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà kọjá. Rodovia Panamericana.  A Rodovia Pan-americana é uma rede de estradas que s...
domingo, 17 de maio de 2020

Ritual de magia negra

›
Oríṣi agbára òkùnkùn kan ti ọmọlẹ́hìn Bolsonaro tó ń lò ọwọ́ rẹ̀ bí àmi ti ohun ìjà kékeré àti  ìtẹríba fún Sátánì. Um tipo de magia negra...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.