Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

sexta-feira, 21 de agosto de 2020

. A “lista negra” do Ministério da Justiça

›
  Ìwé orúkọ ọgọ́rọ̀ọ̀rún àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Bràsíl tí a lè fìyà.  Lista de centenas de brasileiros que podem ser punidos. Tó o bá fẹ́ ìsọf...
segunda-feira, 17 de agosto de 2020

. A condição humana.

›
Àwòrán ṣàpèjúwe ipò mi láìkù síbì kan!  A imagem descreve perfeitamente a minha situação!   Ọ̀wọ́ ọ̀rọ̀ tó wà  nínú èdè, àwọn ọ̀rọ̀ tó máa l...
quinta-feira, 6 de agosto de 2020

Uso de ozônio pelo ânus para tratar Covid-19

›
Nísinsìnyí, àwọn ọmọlẹ́hìn Bolsonaro lè lo òsóònù nípasẹ̀ ihò-ìdí láti sàn Àrún èrànkòrónà ọdún 2019 Agora, b olsominions  podem usar Ozônio...
sábado, 25 de julho de 2020

Torre.

›
Ilé-ìṣọ́, ilé ìṣọ́ gíga, ilé gogoro  (torre)
terça-feira, 14 de julho de 2020

Procedimentos que os pretos devem seguir para sobreviver ao genocídio racial.

›
Àwọn ìlànà tí àwọn adúláwọ̀ gbọ́dọ̀ tẹ̀ lé kí wọ́n lè la ìpaláparun ẹ̀yà ìran já. Procedimentos que pretos devem seguir para sobreviver a...
sábado, 27 de junho de 2020

Etimologia

›
Ìtàn ọ̀rọ̀-èdè (etimologia) Àwọn ọ̀mọ̀wé akẹ́kọ̀ọ́jinlẹ̀ ṣì ń jara wọn níyàn nípa ibi tórúkọ yẹn ti wá. A etimologia desse nome é mui...
sexta-feira, 26 de junho de 2020

Rio São Francisco

›
Odò Fransisi Mímọ́. Rio São Francisco.  Gleisi Hoffmann   o 2 t   S h p o h n d n s o r e d    ·  O tr...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.