Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

domingo, 27 de dezembro de 2020

Teologia da prosperidade

›
  Ẹ̀kọ́ ìsìn kan tó ń gbé lárugẹ pé Ọlọ́run ló ń pín ọrọ̀ (teologia da prosperidade). Ọ̀wọ́ ọ̀rọ̀ tó wà nínú èdè, àwọn ọ̀rọ̀ tó máa lò, àkój...
sábado, 26 de dezembro de 2020

Deus é uma mulher preta.

›
  Ọlọ́run jẹ́ obìnrin aláwọ̀ dúdú kan. Deus é uma mulher preta. Maat ou Ma'at é a deusa da verdade, da justiça, da retidão e da ordem.  ...

Enceradeira

›
                                              Ẹ̀rọ àmúdán (enceradeira).
terça-feira, 22 de dezembro de 2020

Boas festas!

›
  Ẹ kú ọdún Kérésìmesì! Ẹ kú iyedún! Ṣùgbọ́n,  ní orúkọ  Elédùmarè. . . jọ̀wọ́, má gbàgbé láti fún àwọn adúláwọ̀ lókun o.  Feliz Natal! Feli...

Joe Biden

›
  Ààrẹ Joe Biden náà tó ṣẹ̀ṣẹ̀ gorí àlééfà ní Orílẹ̀-Èdè Amẹ́ríkà ti gba abẹ́rẹ́ àjẹsára fún ààrùn Covid-19.  O recém-eleito presidente dos ...
quarta-feira, 16 de dezembro de 2020

Empilhadeira

›
                                Ọkọ̀ àmúga-agbẹ́rù (empilhadeira).
terça-feira, 15 de dezembro de 2020

Excludente de ilicitude

›
  Ìwé àṣẹ láti pa (licença para matar, excludente de ilicitude).   Para Presidente Bolsonaro, o excludente de ilicitude define situações em ...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.