Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

quarta-feira, 6 de janeiro de 2021

Homens-bomba

›
  Àwọn oníbọ́ǹbù apara-ẹni-mọ́-ọ̀tá (homens-bomba). Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se você precisar de mais informações: https://www.inf...
terça-feira, 5 de janeiro de 2021

Programa Espacial da Zâmbia

›
  Ètò Gbalasa Òfuurufú Ilẹ̀ Sámbíà. Programa Espacial da Zâmbia. Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se você precisar de mais informações: ht...
domingo, 3 de janeiro de 2021

Britânicos negros

›
  Àwọn ọmọ ilẹ̀ Brítánì tó jẹ́ aláwọ̀ dúdú (britânicos negros) DNA de esqueleto indica existência de britânicos negros e de olhos azuis há 1...
sábado, 2 de janeiro de 2021

Endoscópio

›
  Ẹ̀rọ aṣàyèwò ẹ̀ya inú ara (endoscópio)  Um endoscópio é um instrumento óptico iluminado, tipicamente delgado e tubular, usado para olhar p...
sexta-feira, 1 de janeiro de 2021

Feliz ano novo!

›
Ẹ kú ọdún titun! Ọdún yìí, mo wí fún ọ, àṣẹ Orí rẹ yóò bá ọ gbé  làyè.  Síwájú sí i, gbobgo àdáwọ́lé wa ni yóò yọrí sí rere láṣẹ Olódùmarè....
quarta-feira, 30 de dezembro de 2020

Salvador Shopping

›
  Ìkórìíra ìran àti ìwà-ipá nínú Ibùdó ìrajà. Ódio racial  e violência no Shopping Center.                     Vidas negras importam! Tó o b...
terça-feira, 29 de dezembro de 2020

Lista de Estados totalmente soberanos

›
  Àkójọ àwọn Orílẹ̀-èdè tí wọ́n ti di òmìnira pátápátá, nítorí tí wọ́n lágbára láti ṣe ìdàgbàsókè àwọn ohun ìjà ogun átọ́míìkì àti àfọnjá tí...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.