Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

terça-feira, 9 de fevereiro de 2021

Etnoastronomia africana.

›
Ìmọ̀ ìjìnlẹ sánmà kan tó gbilẹ̀ láàárín àwọn adúláwọ̀ tí ń gbé nílẹ̀  Áfíríkà. Uma astronomia que florescia entre os pretos de África. Tó o ...
segunda-feira, 8 de fevereiro de 2021

Uma CPI que poderá acontecer nos EUA sobre a Floresta Amazônica.

›
Ìgbìmọ̀ Tó Ń Ṣèwádìí fún Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin orílẹ̀-èdè kan tó lè ṣẹlẹ̀ lórílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà nípa Igbó Kìjikìji Amasónì náà. Uma CPI que pode...
domingo, 7 de fevereiro de 2021

Gastos militares

›
Lẹ́yìn àwọn edé àti wisikí,  àwọn ológun  náwó R$ 652 ẹgbẹ̀rún pẹ̀lú àwọn òdòdó aláwọ̀ mèremère. Após camarões e whiski, militares  gastaram...
quarta-feira, 3 de fevereiro de 2021

Filosofia egípcia no Império Faraônico

›
Ìmọ̀ ọgbọ́n orí Íjíbítì  ní Ilẹ̀ ọbalúayé fáráò. Filosofia egípcia no Império Faraônico. Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se você precisar...

Língua-mãe

›
  Ǹjẹ́ àwọn èdè tó wà lónìí jẹ yọ látinú èdè ìbílẹ̀ kan. Será que línguas modernas evoluíram de uma língua-mãe? Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú ...
terça-feira, 2 de fevereiro de 2021

Genocídio de povos indesejáveis no Brasil

›
Ṣáájú kí a tó pa wa run, ẹ jẹ́ ká lọ síbẹ̀. Ẹ wà lójúfò, ẹ bá wa kálọ, a ó sì já ìjàkadi . Antes de sermos extintos, vamos lá. Seja conscien...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.