Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

terça-feira, 30 de março de 2021

A ideologia nazifascista brasileira

›
  Ní orílẹ̀-èdè Bràsíl, yàtọ̀ sí àwọn ghẹtto àti àdúgbò àwọn akúṣẹ̀ẹ́ gẹ́gẹ́ bí àgọ́ ikú ti násì, ọ̀pọ̀ aláwọ̀ funfun lọ̀gá fẹ́ láti ṣe ìdán...
quinta-feira, 11 de março de 2021

Iorubalândia

›
              Ilẹ̀ Yorùbá (Iorubalândia)
segunda-feira, 8 de março de 2021

Dia Internacional da Mulher

›
               Ayẹyẹ àyájọ́ ọjọ́ obìnrin lágbàáyé.        Dia Internacional da Mulher. 
terça-feira, 2 de março de 2021

Animismo

›
  Ǹjẹ́ àgbáálá ayé ní ẹ̀rí ọkàn?  Será que o universo tem consciência?       Ìgbàgbọ́ pé ẹ̀mí wà nínú ohun gbogbo (animismo)            No a...
segunda-feira, 22 de fevereiro de 2021

Estado da Diáspora Africana

›
  Orílẹ̀-èdè tó ń kó àwọn ọmọ ilẹ̀ Áfíríkà tí wọ́n wà lájò pọ̀. Estado da Diáspora Africana. Olórí ìjọba, M ínísítà Àgbà   (Primeiro-ministr...
sábado, 13 de fevereiro de 2021

"Precisamos atingir Lula na cabeça", diz procuradora.

›
Wọ́n fẹ́ láti bá lu ara ààrẹ Lula tẹ́lẹ̀ lágbárí. Eles queriam atingir o ex-presidente Lula na cabeça.  Ká máà rí ìpániláyà mọ́! - Terrorism...
terça-feira, 9 de fevereiro de 2021

Etnoastronomia africana.

›
Ìmọ̀ ìjìnlẹ sánmà kan tó gbilẹ̀ láàárín àwọn adúláwọ̀ tí ń gbé nílẹ̀  Áfíríkà. Uma astronomia que florescia entre os pretos de África. Tó o ...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.