Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

domingo, 30 de maio de 2021

Eu vou falar pra todo mundo que o socialismo chinês venceu.

›
  Ìṣẹ́gun ìṣesósíálístì pẹ̀lú àwọn  ànímọ́  ilẹ̀ Ṣáínà A vitória do socialismo com características chinesas. Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí ...
quarta-feira, 26 de maio de 2021

Papa diz que Brasil não tem salvação; "muita cachaça e pouca oração."

›
  Póòpù sọ pé: ilẹ̀ Bràsíl yìí ti bàjẹ́ kọjá àtúnṣe; "mímu ọtí àmujù àtàwọn èèyàn kì í sábà ṣe àdúrà."  Papa diz que:  Brasil não ...
quinta-feira, 20 de maio de 2021

Síncope vasovagal

›
  Nígbàtí ìjíròrò náà ń lọ lọ́wọ́ tó bá ṣẹlẹ̀ nínú Ìgbìmọ̀ Tó Ń Ṣèwádìí fún Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin orílẹ̀-èdè, ọ̀gágun kan tó dákú torí ẹ̀rù bà ...
domingo, 16 de maio de 2021

Sonda espacial chinesa pousa em Marte.

›
Ẹ̀rọ atàtaré ìsọfúnni láti gbalasa òfuurufú ilẹ̀ Ṣáínà gúnlẹ̀ sórí Mársì. Sonda espacial chinesa pousa em Marte. Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú...
domingo, 9 de maio de 2021

Feliz Dia das Mães!

›
   Ẹ kú Ayẹyẹ Àyájọ́ Àwọn Ìyá! - Feliz Dia das Mães! Ní paríparí rẹ̀, gbàdúrà pé kí Yèyé Abo-Ọlọ́run wa tó jẹ́ aláwọ̀ dúdú dáàbò bò wa lọ́w...
sábado, 8 de maio de 2021

Atentado terrorista na favela do Jacarezinho.

›
 Ì ṣẹ̀lẹ̀ ìdánilóró ní ọjọ́ kẹfà oṣù karùn-ún ,  ọdún  2021. Atentado terrorista em 6 de maio de 2021. Ìṣìkàpa ọ̀pọ̀ rẹpẹtẹ àwọn aráàlú láti...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.