Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

sábado, 26 de junho de 2021

Traficantes de drogas e policiais estão invadindo Casas de Axé.

›
  Àwọn oníṣòwò oògùn olóró àti ọlọ́pàá ń já wọnú àwọn Ilé Aṣẹ  tipátipá. Traficantes de drogas e policiais estão invadindo Casas de Axé. Tó ...
terça-feira, 22 de junho de 2021

Ameríndios foram à luta contra nazistas e seus aliados.

›
  Àwọn Àmẹ́ríńdíà lọ bá àwọn Násì àtàwọn alájọṣe wọn jà.   Ameríndios foram à luta contra nazistas e seus aliados. Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síw...
segunda-feira, 31 de maio de 2021

Por que a polícia se curva ao branco rico de Alphaville e é violenta na periferia?

›
  1. A bordagem policial no  bairro Alphaville (população branca e rica) - SP.  Ọlọ́pàá rẹ ara rẹ̀ sílẹ̀ ó sì di onígbọràn níwájú oníṣòwò ka...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.