Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

quinta-feira, 29 de julho de 2021

Mundo Pós-Ocidental

›
Ayé lẹ́yìn Ìwọ̀ Oòrùn (Mundo Pós-Ocidental) Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se você precisar de mais informações: https://www.oliverstuen...

Escaravelho sagrado

›
Yímíyímí mímọ́ ọlọ́wọ̀  (escaravelho sagrado)  Ọ̀wọ́ ọ̀rọ̀ tó wà nínú èdè, àwọn ọ̀rọ̀ tó máa lò, àkójọ ọ̀rọ̀ tí ò ń lò lójoojúmọ́, àwọn àkàn...
segunda-feira, 26 de julho de 2021

Elo perdido na história do alfabeto

›
Ìsokọ́ra tí ó pòórá nínú ìtàn álífábẹ́ẹ̀tì. Elo perdido na história do alfabeto.                                           Alfabeto protossi...

China

›
  Orílẹ̀-èdè ṣáínà ​ń náwó ọ̀pọ̀ bílíọ̀nù dọ́là láti ṣe ìdàgbàsókè ìmọ̀ iṣẹ́ ẹ̀rọ rẹ̀. A China está investindo bilhões de dólares para impul...
sexta-feira, 23 de julho de 2021

Minhas fotos.

›
Báwo ni òòrùn ṣe ń mú gbogbo agbára yẹn jáde? Como é que o Sol produz toda essa energia?                       1. Mo jí i - Eu o roubei     ...
segunda-feira, 19 de julho de 2021

Agência espacial indiana.

›
  Ẹ̀ka tó ń bójú tó ètò gbalasa òfuurufú nílẹ̀ Índíà. Agência espacial indiana.    Agência espacial indiana perde contato com sonda durante ...
sexta-feira, 16 de julho de 2021

Ore pelo capetão!

›
Béélísébúbù tún ń fetísílẹ̀ sí àwọn àdúrà tí a gbà fún ihò-ìdí  ààrẹ tó jẹ́ ọ̀gá nínú ẹgbẹ́ ọmọ ogun. Belzebu também ouve orações oferecidas...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.