Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

sábado, 21 de agosto de 2021

O que não é e o que é.

›
        Ohun tí kò jẹ́ àti ohun tí ó jẹ́.         O que não é e o que é. Ọ̀wọ́ ọ̀rọ̀ tó wà nínú èdè, àwọn ọ̀rọ̀ tó máa lò, àkójọ ọ̀rọ̀ tí ò ...

Cantiga para Oxalá

›
Orin fún Òṣàlá (cantiga para Oxalá)                           O lùtumọ̀ ( t radutor):   Olùk ọ́  Orlandes. Oní sáà àwúre a ń láṣẹ, oní sáà à...
segunda-feira, 16 de agosto de 2021

Greve dos caminhoneiros

›
Lọ́jọ́ Oṣù kẹsàn-án ọdún 07, 2021, à wọn awakọ̀ akẹ́rù ilẹ̀ Bràsíl tí wọ́n jẹ́ ọmọlẹ́hìn tàbí alátìlẹyìn ààrẹ Bolsonaro  yóò daṣẹ́ sílẹ̀, wọ...
terça-feira, 10 de agosto de 2021

Uma marcha triunfante com antigos tanques de guerra em Brasília.

›
Ìtọ́wọ̀ọ́rìn aláyọ̀ ​ìṣẹ́gun pẹ̀lú àwọn tánkì ogun àtijọ́ ní olúìlú Bràsílíà. Uma marcha triunfante com antigos tanques de guerra em Brasíli...
segunda-feira, 9 de agosto de 2021

China: Desenvolvimento e socialismo de mercado.

›
  Àkọlé ìwé náà:  ilẹ̀ Ṣáínà: Ìdàgbàsókè àti ìṣesósíálístì ọjà. Título: China: Desenvolvimento e socialismo de mercado. Autor: Elias Jabbour...
domingo, 8 de agosto de 2021

Quadro de medalhas olímpicas de Tóquio -2020

›
Tábìlì àmì ẹ̀yẹ òlímpíkì ní Tokyo 2020 Quadro de medalhas olímpicas de Tóquio -2020 1. CHINA (China +Taipé Chinês + Hong kong) :  41 (ouro),...
sábado, 7 de agosto de 2021

Motociata do orgulho gado

›
  Ìtọ́wọ̀ọ́rìn aláyọ̀ ​ìṣẹ́gun àwọn alùpùpù ​láti fi hàn pé inú wa dùn sí jíjẹ́ tá a jẹ́ ẹran ọ̀sìn. Motociata do orgulho gado. Tó o bá fẹ́ ...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.