Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

quarta-feira, 12 de janeiro de 2022

- Golpe da barriga.

›
Ọgbọ́n ẹ̀wẹ́ náà tó máa ń jáde wá  láti  ikùn.   O golpe da barriga. https://www.diariodocentrodomundo.com.br/essencial/caiu-na-rede-bolsona...
sábado, 18 de dezembro de 2021

Coca-Cola mexicana

›
Ìgò Kòká Kolà kan tó wá láti ilẹ̀ Mẹ́síkò. Uma garrafa de Coca-Cola mexicana. Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se você precisar de mais in...
sexta-feira, 17 de dezembro de 2021

Seleção Haitiana de Futebol

›
Ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀ ọmọorílẹ̀-èdè Hàítì. Seleção Haitiana de Futebol. Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se você precisar de mais info...
quinta-feira, 9 de dezembro de 2021

Instrumentos de corda árabes

›
  Àwọn ohun èlò ìkọrin olókùn tín-ín-rín tó wá látinú  àwọn ará Arébíà. Instrumentos de corda árabes. 1. Al-oud ➜   alaúde, violão, guitarra...
domingo, 5 de dezembro de 2021

- Ordem Dos Capelães do Brasil

›
  Ẹgbẹ́ Àwọn Àlùfáà ní Bràsíl.  Ordem Dos Capelães do Brasil. Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se você precisar de mais informações: http...
quarta-feira, 1 de dezembro de 2021

- Partido Comunista Chinês

›
Ẹgbẹ́ Kọ́múnístì ilẹ̀ Ṣáínà. Partido Comunista Chinês. Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se você precisar de mais informações: https://www....

- Um jovem preto é torturado e arrastado pelas ruas de SP

›
Ìdálóró:   Ọlọ́pàá tó máa ń kórìíra ẹ̀yà mìíràn fa ọkunrin ọ̀dọ́ aláwọ̀ dúdú kan lẹ́yìn alùpùpù rẹ.  Tortura: Policial racista arrasta um jo...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.