Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

domingo, 13 de fevereiro de 2022

- Criminalização do capitalismo

›
  A fẹ́ òfin kan tó ka kapitálísíìmù léèwọ̀. Queremos uma lei que proíba o capitalismo. Desde o começo, o capitalismo (maior genocida da his...
domingo, 6 de fevereiro de 2022

- CSTO

›
Àjọ Àdéhùn ààbò àjọkọ́wọ́tì. Organização do Tratado de Segurança Coletiva (CSTO). Wikipéédíà (ìwé-ìmọ̀ ọ̀fẹ́) tá a ṣèwádìí nínú ẹ̀ sọ pé - ...
quarta-feira, 2 de fevereiro de 2022

- A questão do Rio Pirara (1829-1904)

›
Àgbègbè kan tó jẹ́ apá kan Ilẹ̀ Bràsíl tẹ́lẹ̀ àmọ́ táwọn Adúláwọ̀ ará Gùyánà ti òde òní ń ṣàkóso. Uma área que já foi parte do Brasil, mas q...
segunda-feira, 31 de janeiro de 2022

- RJ: regime nazifascista ocupa Jacarezinho para aterrorizar o povo preto com limpeza étnica, ódio racial e tortura.

›
    Àwọn ìròyìn bíi pípa odindi ẹ̀yà run,  ìkórìíra kẹ́lẹ́yàmẹ̀yà,  ìwà ìkà sí ìran ènìyàn  àti ìròyìn àwọn apániláyà. Notícias como limpeza...
sábado, 22 de janeiro de 2022

Primavera Árabe

›
  Àwọn ìdìtẹ̀ ńlá tó ti ṣẹlẹ̀ nínú Àárín Gbùngbùn Ìlà Oòrùn Ayé àti  Àríwá ilẹ̀ Áfíríkà, bẹ̀rẹ̀ láti oṣù Ọ̀pẹ (oṣù kéjìlá ọdún), ọdún 2010 G...
quinta-feira, 20 de janeiro de 2022

- Colocar cor em alguns personagens históricos.

›
 1.  Ìwà ti fífi àwọ̀ kun àwọn ẹni gidi kan nínú ìtàn náà  láti sọ wọ́n di aláwọ̀ dúdú.    Ato de colorir alguns personagens reais da histór...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.