Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

terça-feira, 12 de abril de 2022

- Frente Sandinista de Libertação Nacional (FSLN)

›
  Ẹgbẹ́ Ọmọ Ogun àwọn Ọlọ̀tẹ̀ Atẹ̀lé Ìlànà Ọ̀gọ́sítọ́sì Késárì Sándínò fún Ìdáǹdè Torílẹ̀-èdè. Frente Sandinista de Libertação Nacional (FSL...
sábado, 2 de abril de 2022

- Companhias de fast-food

›
  Àwọn iléeṣẹ́ tó ń ta oúnjẹ àyáragbọ́  (companhias de fast-food). Oúnjẹ àyáragbọ́ (fast food) é o nome genérico dado ao consumo de refeiçõe...
terça-feira, 29 de março de 2022

- Processo

›
  Ọ̀nà-ìgbàṣiṣẹ (processo) Sequência contínua de fatos ou operações que apresentam certa unidade ou que se reproduzem com certa regularidade...

Mototáxi

›
  Lẹ́yìn náà, ó gun ọ̀kadà, ó sì gba ìpàdé kan lọ. Depois, pegou um mototáxi e foi para uma reunião. Ọ̀wọ́ ọ̀rọ̀ tó wà nínú èdè, àwọn ọ̀rọ̀ ...
Um comentário:
segunda-feira, 28 de março de 2022

Socialismo chinês.

›
  Ìkórìíra àwọn ará ìhà Ìwọ̀ Oòrùn ayé lòdì sí  ìṣesósíálístì pẹ̀lú àwọn ànímọ́ ilẹ̀ Ṣáínà tó yóò mú wa lọ sí àwọn ọjọ́ òkùnkùn àti  àìlágbá...

Campanha eleitoral antecipada

›
  Ìpolongo ìbò tó ń ṣe ṣáájú (campanha eleitoral antecipada) Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se você precisar de mais informações: https:...
domingo, 27 de março de 2022

Fosforescência

›
  Fósífórísẹ́ǹsì (fosforescência, luminescência, fotoluminescência ) "A fosforescência ocorre quando uma substância é capaz de absorver...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.