Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

segunda-feira, 27 de junho de 2022

- Oito indígenas detidos após conflitos com forças policiais em Amambi (MS)

›
  Lẹ́yìn ìpẹ̀yàrun àti pípa ẹ̀yà ìran run, àwọn adájọ́ Bràsíl pàṣẹ pé kí wọ́n fòfin mú mẹ́jọ nínú àwọn  ọ mọ ìbílẹ̀ tó wà ní Ìpínlẹ̀ Mato Gr...
domingo, 26 de junho de 2022

- Tropa de Choque fuzila jovens Guarani Kaiowá em Amambai, MS

›
Nítorí àwọ̀ ara àti ìpilẹ̀ ẹ̀yà-ìran, àwọn ọlọ́pàá apaná ìjọ̀ngbọ̀n ti yìnbọn pa àwọn Ọmọ Ìbílẹ̀ Bràsíl. Indígenas do Brasil foram fuzilados...
sexta-feira, 24 de junho de 2022

Protestos e greve nacional no Equador

›
  Àwọn ọmọ ilẹ̀ Ẹ̀kùàdọ̀r ti wà lẹ́nu ìdìtẹ̀ sí ìjọba  O povo do Equador já está em estado de revolta contra o governo. https://bancariospa....
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.