Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

quinta-feira, 21 de julho de 2022

- China socialista vai liderar a nova ordem mundial

›
  Ṣáínà Sósíálístì yóò ṣáájú ètò ayé titun náà. China socialista vai liderar a nova ordem mundial. Àwọn ará Éṣíà  wọ̀nyí   ni àwọn baba ńlá ...
terça-feira, 12 de julho de 2022

Primeira vice-presidenta preta da Colômbia

›
  Francia Elena Márquez Mina tó jẹ́  igbákejì ààrẹ aláwọ̀ dúdú àkọ́kọ́ fún ilẹ̀ Kòlómbìà.  Francia Elena Márquez Mina, primeira vice-preside...

Caribe Food

›
   Ilé oúnjẹ Kàríbẹ́ánì (restaurante caribenho) Àdírẹ́ẹ̀sì (endereço): Santa Bárbara d'Oeste, SP Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se v...

A luta dos patriotas brasileiros para destruir nosso país

›
  Ìjàkadì àwọn ọmọ ilẹ̀ Bràsíl onítara tí wọ́n nífẹ̀ẹ́ orílẹ̀-èdè wọn láti pa orílẹ̀-èdè wa run. A luta dos patriotas brasileiros para destr...

- Não aceite terrorismo de bolsominions

›
  Má ṣe gba ìpániláyà àwọn ọmọlẹ́yìn ààrẹ Bolsonaro Não aceite terrorismo de bolsomínions. Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se você precis...
segunda-feira, 11 de julho de 2022

- Atentados terroristas no Brasil

›
  Gbogbo ọmọlẹ́hìn ààrẹ Bolsonaro tó dìhámọ́ra lè yí padà di apániláyà. - Cada bolsomínio armado pode se transformar em terrorista. - Cada B...
sábado, 2 de julho de 2022

Apedemak

›
  Òrìṣà Kìnìún tó rí bí  ẹ̀dá ènìyàn  (o Deus Leão em forma humana).     (Pa-ir-meki, Apedemak) Òòṣà àwọn ará Kúṣì kan tó ní í ṣe pẹ̀lú ogu...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.