Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

quinta-feira, 28 de julho de 2022

O general negro americano que pode salvar nossa democracia

›
  Ọ̀gágun àgbà aláwọ̀ dúdú fún ilẹ̀ Amẹ́ríkà tó lè gba ìjọba tiwa-n-tiwa wa là. O general negro americano que pode salvar nossa democracia. ...
terça-feira, 26 de julho de 2022

- Ditadura demcrática personalizada.

›
  Ìjọba apàṣẹwàá-dẹmọkrátíkì tó bá ohun tó ń ṣe oníkálùkù mu. Ditadura demcrática personalizada.                                 Olùkọ́ Orla...

- História da filosofia africana

›
  Íjíbítì: Ìtàn àtijọ́ ti ìmọ̀ ọgbọ́n orí Áfríkà. Egito: História antiga da filosofia africana.                                       Olùkọ̀...
segunda-feira, 25 de julho de 2022

Dia da Mulher Negra Latino-americana e Caribenha

›
  Mo kí ẹ kúu ti Ọjọ́ Obìnrin Adúláwọ̀ Látìn-Amẹ́ríkà àti Kàríbẹ́ánì rẹ o!  Feliz Dia da Mulher Negra Latino-americana e Caribenha! Tó o bá ...
domingo, 24 de julho de 2022

Panteão aborígene

›
  Gbogbo àgbájọ òrìṣà àwọn Ọmọ Onílẹ̀ Austrálíà (panteão aborígene) https://www.infoescola.com/antropologia/aborigenes/ 1.  Julunggul ( Òṣùm...
quinta-feira, 21 de julho de 2022

- China socialista vai liderar a nova ordem mundial

›
  Ṣáínà Sósíálístì yóò ṣáájú ètò ayé titun náà. China socialista vai liderar a nova ordem mundial. Àwọn ará Éṣíà  wọ̀nyí   ni àwọn baba ńlá ...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.