Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

quarta-feira, 10 de agosto de 2022

Calendário Kamita

›
  Kàlẹ́ńdà àwọn ará Kẹ́mẹ́ẹ̀tì Calendário do povo de Kemet. Feliz feliz ano novo 6259 para todos os africanos autênticos (Kamitas). Kàlẹ́ńdà...
terça-feira, 9 de agosto de 2022

Aulas de yorubá

›
  Àwọn ìdánilẹ́kọ̀ọ́ èdè yorùbá (aulas de yorubá) Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se você precisar de mais informações: https://aulasdeyo...

- Bolsonaro é expulso de churrascaria em São Paulo

›
  Nígbà tí wọ́n lé ààrẹ Bolsonaro kúrò ní ilé  oúnjẹ  yíyan ẹran. Quando o presidente Bolsonaro foi expulso da churrascaria. Tó o bá fẹ́ ìsọ...
segunda-feira, 8 de agosto de 2022

- Terrorismo semioficial e estatal

›
 1.  Ìṣedánilóró nílẹ̀  Bìràsílì   ( t errorismo no Brasil)  Àwọn àṣẹ Alákòóso Àgbà lórí ọ̀kẹ́ àìmọye ẹgbẹ́ ọmọ ogun àwọn ọmọlẹ́hìn ààrẹ Bol...
sábado, 30 de julho de 2022

Um general negro dos Estados Unidos para desnazificar o Brasil

›
Ọ̀gágun àgbà aláwọ̀ dúdú ti ilẹ̀ Amẹ́ríkà kan láti  fòpin sí ìpániláyà Násì ní Bràsíl. Um general negro dos Estados Unidos para desnazificar...
quinta-feira, 28 de julho de 2022

O general negro americano que pode salvar nossa democracia

›
  Ọ̀gágun àgbà aláwọ̀ dúdú fún ilẹ̀ Amẹ́ríkà tó lè gba ìjọba tiwa-n-tiwa wa là. O general negro americano que pode salvar nossa democracia. ...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.