Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

sexta-feira, 19 de agosto de 2022

- O presidente que tentou roubar um celular

›
  Ààrẹ tó ti gbìyànjú láti jí fóònù alágbèéká kan gbé O presidente que tentou roubar um celular.   Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se voc...

- Filosofia ocidental

›
  Filọ́sọ́fi ti Ìwọ Oòrùn ayé (filosofia ocidental).  Oríṣi ìfẹ́ ìmọ̀ kan tó jẹ́ onímájèlé tó sì máa ń gbé kíkórìíra ẹ̀yà mìíràn lárugẹ - Um...
quarta-feira, 10 de agosto de 2022

Calendário Kamita

›
  Kàlẹ́ńdà àwọn ará Kẹ́mẹ́ẹ̀tì Calendário do povo de Kemet. Feliz feliz ano novo 6259 para todos os africanos autênticos (Kamitas). Kàlẹ́ńdà...
terça-feira, 9 de agosto de 2022

Aulas de yorubá

›
  Àwọn ìdánilẹ́kọ̀ọ́ èdè yorùbá (aulas de yorubá) Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se você precisar de mais informações: https://aulasdeyo...

- Bolsonaro é expulso de churrascaria em São Paulo

›
  Nígbà tí wọ́n lé ààrẹ Bolsonaro kúrò ní ilé  oúnjẹ  yíyan ẹran. Quando o presidente Bolsonaro foi expulso da churrascaria. Tó o bá fẹ́ ìsọ...
segunda-feira, 8 de agosto de 2022

- Terrorismo semioficial e estatal

›
 1.  Ìṣedánilóró nílẹ̀  Bìràsílì   ( t errorismo no Brasil)  Àwọn àṣẹ Alákòóso Àgbà lórí ọ̀kẹ́ àìmọye ẹgbẹ́ ọmọ ogun àwọn ọmọlẹ́hìn ààrẹ Bol...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.