Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

sábado, 27 de agosto de 2022

- Dia Mundial da Medicina Tradicional Africana

›
  Ọjọ́ Ìṣègùn Ìbílẹ̀ Áfíríkà Lágbàáyé. Dia Mundial da Medicina Tradicional Africana. Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se você precisar de ...
terça-feira, 23 de agosto de 2022

- Marca Fria

›
Oníṣẹ́ bíríkìlà kan tá a pe orúkọ rẹ̀ ní Àmì Tútù Um pedreiro chamado Marca Fria. Àwọn gbèsè (dívidas) :  Restante: 315 pago: 150  reais + 1...

- Criaturas imortais

›
 Àwọn ẹ̀dá aláìleèkú (criaturas imortais):  1. P lanária   2. H idra 3.  Turritopsis dohrnii ( água-viva imortal) Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwáj...
segunda-feira, 22 de agosto de 2022

O coração de D. Pedro I que chegou ao Brasil é uma relíquia macabra e inútil

›
  Ọ̀kan-àyà Olú Ọba Dom Pétérù 1k tó ti dé sí Bràsíl ni ohun ìrántí burúkú, ó sì jẹ́ aláìwúlò. O coração de D. Pedro I que chegou ao Brasil ...

- Ceitec

›
  Ilé iṣẹ́ Ìtayọlọ́lá ní Tẹknọ́lọ́jì  Ẹ̀ lẹ́ktrónìkì Tó ti ní ìtẹ̀síwájú (Ceitec).  Centro de Excelência em Tecnologia Eletrônica Avançada (...
sexta-feira, 19 de agosto de 2022

- O presidente que tentou roubar um celular

›
  Ààrẹ tó ti gbìyànjú láti jí fóònù alágbèéká kan gbé O presidente que tentou roubar um celular.   Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se voc...

- Filosofia ocidental

›
  Filọ́sọ́fi ti Ìwọ Oòrùn ayé (filosofia ocidental).  Oríṣi ìfẹ́ ìmọ̀ kan tó jẹ́ onímájèlé tó sì máa ń gbé kíkórìíra ẹ̀yà mìíràn lárugẹ - Um...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.