Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

domingo, 4 de dezembro de 2022

Centro de Estudos da Política Songun – Brasil

›
  Ibùdó fún ṣíṣe ìwádìí nípa ìṣèlú Songun lórílẹ̀-èdè Bràsíl. Centro de estudo da política songun no Brasil.   Òrìṣà Kìnìún tó rí bí  ẹ̀dá è...
Um comentário:
sábado, 3 de dezembro de 2022

- Indígenas bolsonaristas invadem aeroporto de Brasília

›
    Àwọn Àmẹ́ríńdíà tí wọ́n jẹ́ ọmọlẹ́yìn ààrẹ Bolsonaro fi ẹ̀hónú wọn hàn pápákọ̀ òfuurufú  olúìlú Bràsílíà láti fún àwọn ọ̀tá rẹ̀ lágbára....
Um comentário:

Ácaro (kòkòrò mite)

›
  Kòkòrò tó lè bá ara rẹ jà, ó lè fa ikọ́ fée, tàbí ifo. Ácaro que pode provocar reações alérgicas, asma, ou eczemas. K òkòrò mite tí ò ní ...
Um comentário:
terça-feira, 29 de novembro de 2022

- Cantiga: Eu sou patriotário.

›
Orin:  Èmi ni òmùgọ̀ kan tí ó nífẹ̀ẹ́ orílẹ̀-èdè  rẹ̀ . Cantiga: Eu sou um patriotário. Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se você precisar ...
Um comentário:
quarta-feira, 23 de novembro de 2022

Um caminho quíntuplo para empoderar pessoas pretas

›
Ọ̀nà kan tó jẹ́ alápá márùn-ún láti fún àwọn aláwọ̀ dúdú lágbára. Um caminho quíntuplo para empoderar pessoas pretas. 1. Pan-africanismo. Um...
Um comentário:
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.