Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

terça-feira, 13 de dezembro de 2022

Grupos terroristas atacaram Brasília

›
Àwọn ẹgbẹ́ akópayàbán (àwọn ọmọlẹ́yìn ààrẹ Bolsonaro) tí wọ́n dó sí iwájú orílé iṣẹ́ ẹgbẹ́ ọmọ ogun ti Orílẹ̀-Èdè Bràsíl wá gbéjà ko ìlú Brà...
Um comentário:
segunda-feira, 12 de dezembro de 2022

IBAS

›
  Ẹgbẹ́ àpérò tó máa ń jẹ́ kí Íńdíà, Bràsíl àti Gúúsù Áfíríkà lè máa bára wọn sọ̀rọ̀. Fórum de Diálogo Índia-Brasil-África do Sul. Tó o bá ...
Um comentário:

Organizações internacionais sediadas em África

›
  Àwọn àjọ àgbáyé tí wọ́n fi Áfíríkà ṣe ibùjókòó.   Organizações internacionais sediadas em África. 1. Ìmùlẹ̀ Àwọn Orílẹ̀-Èdè Arébíà - Liga ...
Um comentário:
segunda-feira, 5 de dezembro de 2022

- Bairro de Santa Fé em Bogotá, Colômbia.

›
  Àdúgbò Ìgbàgbọ́ Mímọ́ tó wà ní Olúìlú  Bogotá, ní Kòlóńbíà. Bairro de Santa Fé em Bogotá, Colômbia. Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se ...
Um comentário:
domingo, 4 de dezembro de 2022

Centro de Estudos da Política Songun – Brasil

›
  Ibùdó fún ṣíṣe ìwádìí nípa ìṣèlú Songun lórílẹ̀-èdè Bràsíl. Centro de estudo da política songun no Brasil.   Òrìṣà Kìnìún tó rí bí  ẹ̀dá è...
Um comentário:
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.