Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

quinta-feira, 29 de dezembro de 2022

Bolsonaro tomará posse novamente em 1º de janeiro de 2023.

›
Bolsonaro  yóò ṣàkóso àwọn ọmọlẹ́yìn rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ààrẹ lẹ́ẹ̀kejì ní Erékùṣù ìdọ̀tí kan tí ó wà nínú Òkun Pàsífíìkì. Bolsonaro governará seu...
Um comentário:
terça-feira, 27 de dezembro de 2022

- Língua Khoisan

›
  Èdè kan tí kò rọrùn láti sọ. Uma língua que não é fácil de falar. Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se você precisar de mais informações:...
Um comentário:
segunda-feira, 26 de dezembro de 2022

- Bolsomínios terroristas

›
  Ṣé a nílò ìrànlọ́wọ́  àwọn ọmọ ogun orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà láti yin bọ́ǹbù àwọn ẹgbẹ́ apániláyà tí wọ́n dó sí iwájú orílé iṣẹ́ ẹgbẹ́ ọmọ ogun...
quarta-feira, 14 de dezembro de 2022

Arco-íris

›
  A óò ní òṣùmàrè púpọ̀ síi lọ́jọ́ iwájú. Teremos mais arco-íris no futuro. Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se você precisar de mais info...
Um comentário:
terça-feira, 13 de dezembro de 2022

Grupos terroristas atacaram Brasília

›
Àwọn ẹgbẹ́ akópayàbán (àwọn ọmọlẹ́yìn ààrẹ Bolsonaro) tí wọ́n dó sí iwájú orílé iṣẹ́ ẹgbẹ́ ọmọ ogun ti Orílẹ̀-Èdè Bràsíl wá gbéjà ko ìlú Brà...
Um comentário:
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.