Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

domingo, 27 de agosto de 2023

Dia do patriotário (08/01/2023)

›
   Ayẹyẹ ọjọ́ onítara èké (òpè, òmùgọ̀ tàbí asínwín) tó nífẹ̀ẹ́ orílẹ̀-èdè rẹ̀. Dia do falso patriota (ignorante, estúpido ou insano). Ọjọ́ ...
quinta-feira, 3 de agosto de 2023

- Universo em bloco

›
  Tíọ́rì àgbáálá ayé kan tó dà bí búlọ́ọ̀kù uma teoria do universo em forma de bloco. Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se você precisar de...
terça-feira, 18 de julho de 2023

- Questões fundamentais

›
  Àwọn ìbéèrè pàtàkì (questões fundamentais)  Kéèyàn tó lè ní ojúlówó ìbàlẹ̀ ọkàn, èèyàn ní láti rí ìdáhùn sáwọn ìbéèrè pàtàkì yìí - Se você...
quarta-feira, 5 de julho de 2023

- Òwe àwọn ará Yorùbá (provérbio yorubá)

›
Nígbà tí kòkòrò mùkúlú náà di labalábá kò tún pa dà rákò lórí ilẹ̀ mọ́. A lagarta quando vira borboleta nunca mais rasteja.  Ọ̀wọ́ ọ̀rọ̀ tó ...
sexta-feira, 16 de junho de 2023

Oyotunji African Village

›
  Abúlé àwọn ará Yorùbá kan tó ń jẹ́  Ọ̀yọ́túnjí  lórílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà. Uma vila yorubá chamada Oyotunji nos EUA. Oyotunji African Village é...
quinta-feira, 15 de junho de 2023

- Montadora de automóveis

›
Ilé iṣẹ́ tí ń ṣe ọkọ̀ ìrìnnà (empresa fabricante de veículos)                                            Frederick Patterson ao lado de seu ...
quinta-feira, 8 de junho de 2023

- Sociedade matrilinear

›
  Àwùjọ tí ìlà ìran jẹ́ ti ìyá  Sociedade matrilinear. Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se você precisar de mais informações: https://www....
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.