Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

quarta-feira, 25 de outubro de 2023

Primeiro genocídio televisionado

›
Ìparun ẹ̀yà àwọn ará Palẹ́sìnì nínú Àgbègbè Gásà (2023) ni ìpẹ̀yàrun  àkọ́kọ́ náà tí aráyé ń wo ìran àrímáleèlọ náà lórí tẹlifíṣọ̀n, bó ṣe ń...

Genocídio dos palestinos na Faixa de Gaza

›
  A gbọ́dọ̀ ka ìparun ẹ̀yà àwọn ará Palẹ́sìnì nínú Àgbègbè Gásà (2023) àti ìpalápalù  àwọn ará aláwọ̀ dúdú àti àwọn ará Àmẹ́ríńdíà tí ó wà n...
sexta-feira, 6 de outubro de 2023

- Colonialismo africano na Península Ibérica

›
Ètò ìgbókèèrè-ṣàkóso àwọn ará áfíríkà ní àgbègbè Iberia. Colonialismo africano na Península Ibérica. Estados e dinastias mouros no norte de ...
quinta-feira, 5 de outubro de 2023

- Operação punho de ferro no Haiti

›
Ìgbésẹ̀ ológun ọrùn ọwọ́ (ìkúùkù) irin ní Orílẹ̀-èdè Hàítì. Operação punho de ferro no Haiti. Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se você pre...
domingo, 3 de setembro de 2023

- Liga dos Camponeses Pobres

›
Ẹgbẹ́ Àwọn Àgbẹ̀ Tó Jẹ́ Òtòṣì. Liga dos Camponeses Pobres. Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se você precisar de mais informações: https://...
domingo, 27 de agosto de 2023

Dia do patriotário (08/01/2023)

›
   Ayẹyẹ ọjọ́ onítara èké (òpè, òmùgọ̀ tàbí asínwín) tó nífẹ̀ẹ́ orílẹ̀-èdè rẹ̀. Dia do falso patriota (ignorante, estúpido ou insano). Ọjọ́ ...
quinta-feira, 3 de agosto de 2023

- Universo em bloco

›
  Tíọ́rì àgbáálá ayé kan tó dà bí búlọ́ọ̀kù uma teoria do universo em forma de bloco. Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se você precisar de...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.