Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

segunda-feira, 13 de novembro de 2023

Kilombo da nega

›
  Abúlé àdádó obìnrin aláwọ̀ dúdú. Kilombo da nega.  Abúlé ìkọ̀kọ̀ obìnrin aláwọ̀ dúdú. Kilombo da nega.   Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i ...

O antissemitismo judaico contra o povo semita palestino.

›
  Ìkórìíra tí àwọn Júù ní sáwọn ará Palẹ́sìnì tó jẹ́ Sémí ní orílẹ̀-èdè Ísírẹ́lì mú kí ìjọba Násì tàbí áńgẹ́lì ikú tá a pe orúkọ rẹ̀ ní Bẹ́ń...
quarta-feira, 8 de novembro de 2023

Antissemitismo

›
Inúnibíni sí àwọn ará Sémítì (àwọn ará palẹ́sìnì)  tí wọ́n ń bá ìpakúpa àwọn ènìyàn wọn jà. Perseguição aos semitas (palestinos) que lutam c...

Quem é mais forte?

›
  Ta ló lágbára jù? - Quem é mais forte?   Certa vez, uma pedra disse: “Eu sou forte”. Ouvindo isso, o ferro falou: “Eu sou mais forte que v...
quinta-feira, 26 de outubro de 2023

Minhas estratégias militares para o mundo árabe derrotar seus inimigos.

›
  Àwọn ọgbọ́n ẹ̀wẹ́ ológun mi fún ayé àwọn ará àrábù ṣẹ́gun  àwọn ọ̀tá rẹ̀. Minhas estratégias militares para o mundo árabe derrotar seus in...
quarta-feira, 25 de outubro de 2023

Primeiro genocídio televisionado

›
Ìparun ẹ̀yà àwọn ará Palẹ́sìnì nínú Àgbègbè Gásà (2023) ni ìpẹ̀yàrun  àkọ́kọ́ náà tí aráyé ń wo ìran àrímáleèlọ náà lórí tẹlifíṣọ̀n, bó ṣe ń...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.