Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

domingo, 7 de julho de 2024

0 primeiro Deus da humanidade

›
Ọlọ́run kan tí a ń pè ní Kaang (ní èdè Bushman) ni Olú-ọlọ́run àkọ́kọ́ nínú aráyé tàbí Ọlọ́run náà tó tíì pẹ́ jù lọ lára àwọn Ọlọ́run tí a m...
terça-feira, 2 de julho de 2024

Natureza

›
            Àdánidá (natureza) 1. Yèyé Ìṣẹ̀dá, àràmàǹdà obìnrin náà, ló dá wa, àwa ni àdánidá, a ó sì padà s   í i - A mãe Natureza, a mulhe...
sexta-feira, 19 de abril de 2024

Genocídio e a limpeza étnica através da fome.

›
  Pípa ẹ̀yà run àti pípa ìran run nípasẹ̀ ebi. Genocídio e a limpeza étnica através da fome. Ọ̀wọ́ ọ̀rọ̀ tó wà nín ú èdè, àwọn ọ̀rọ̀ tó máa ...
sexta-feira, 22 de dezembro de 2023

A tempestade não luta para derramar a água do coco.

›
Ìjì kìí jà kó da omi inu àgbọn nù. A tempestade não consegue esvaziar (afetar) a água dentro do coco. Ọ̀wọ́ ọ̀rọ̀ tó wà nín ú èdè, àwọn ọ̀rọ...
segunda-feira, 11 de dezembro de 2023

Alguns países são como elefantes amarrados a um pé de milho.

›
  Àwọn orílẹ̀-èdè kan dà bí erin tí wọ́n so mọ́ igi àgbàdo.  Àwọn àpẹẹrẹ títayọ méjì nínú àwọn orílẹ̀-èdè tí kò tíì dàgbàsókè:  Bràsíl àti O...
sábado, 2 de dezembro de 2023

Xamãs do povo yanomami nos alertam que: "O céu cairá sobre nós".

›
Àwọn aṣáájú ẹ̀sìn ìbílẹ̀ àwọn ará Yanomami kìlọ̀ fún wa pé: " Sánmọ̀ yóò já bọ́ sórí wa".   Xamãs do povo yanomami nos alertam que...
quinta-feira, 23 de novembro de 2023

O mito da brasilidade

›
  Àròsọ náà tí gbogbo wa jẹ́ àwọn ará Bràsíl. O mito da brasilidade. Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se você precisar de mais informações...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.