Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

segunda-feira, 12 de agosto de 2024

A última etapa da escravidão.

›
Tó o bá jẹ́ ọ̀mọ̀wé abínibí kan tó ń ronú níbàámu pẹ̀lú àṣà amúnisìn náà nítorí pé kò mọ èdè àti àṣà ìbílẹ̀ àwọn baba ńlá wọn; ọ̀pọ̀ àwọn Al...
terça-feira, 23 de julho de 2024

Inteligência, uma propriedade biológica – Cognição no mundo vegetal.

›
  Ọgbọ́n-òye, ànímọ́ kan tó wà nínú àwọn ohun alààyè - Ìfòyemọ̀ ní ayé ewéko. Inteligência, uma propriedade biológica – Cognição no mundo ve...

Inteligência, uma propriedade bioógica - Cognição no mundo microscópico

›
Ọgbọ́n-òye, ànímọ́ kan tó wà nínú àwọn ohun alààyè - Ìfòyemọ̀  ní ayé àwọn ohun alààyè tín-tìn-tín  ti  àwọn sẹ́ẹ̀lì abẹ̀mí, àwọn bakitéríà ...
domingo, 21 de julho de 2024

Cinco ideias erradas que temos sobre a evolução

›
  Àwọn àṣìlóye márùn-ún tá a ní nípa ẹfolúṣọ̀n. Cinco ideias erradas que temos sobre a evolução. Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se você ...
sábado, 20 de julho de 2024

Pirahã

›
Ẹ̀yà ìran kan tí a ń pè ní Pirahã. Uma etnia chamada Pirahã. Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se você precisar de mais informações: https:...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.