Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

sábado, 5 de outubro de 2024

Escala de Kardashev

›
Ìwọ̀n ìdàgbàsókè ọgbọ́n-iṣẹ́ ẹ̀rọ tí ìlàjú kan ní. O grau de desenvolvimento tecnológico de uma civilização. Tipo I: Uma civilização capaz d...

Existência

›
Wíwà tá a wà yìí kì í ṣe nǹkan míì ju àlá kúántù kan lásán ní àárín òfo ayérayé. Essa existência que temos nada mais é do que um mero sonho ...
sexta-feira, 4 de outubro de 2024

Biologia da ressurreição

›
Kí nìdí tí "bàíọ́lọ́jì àjíǹde" ń  gbilẹ̀  jákèjádò ayé? Por que a “biologia da ressurreição” está ganhando força no mundo todo? Tó...
terça-feira, 1 de outubro de 2024

Sistema de Gestão de Identidade Federal (NIMS)

›
Ètò Ìṣàkóso  Ìdánimọ̀ Ìjọba Àpapọ̀ (NIMS)  Sistema de Gestão de Identidade Federal (NIMS).   E jẹ kí á sọ ẹni tí a jẹ fún yín - Deixe-nos di...
sábado, 28 de setembro de 2024

Será que Jesus era homossexual?

›
Ǹjẹ́ Jésù jẹ́ abẹ́yà-kan-náà-lòpọ̀?  Será que Jesus era homossexual? Ìhìn Rere Máàkù tó jẹ́ àṣírí (Evangelho Secreto de Marcos) :   https://...
quarta-feira, 18 de setembro de 2024

Um ritual satânico em que terroristas e latifundiários costumavam sacrificar ameríndios.

›
Ààtò Sátánì kan tí  àwọn  apániláyà  àti àgbẹ̀ aládàá ńlá máa ń fi Àmẹ́ríńdíà rúbọ. Um ritual satânico em que terroristas e latifundiários c...
domingo, 15 de setembro de 2024

Por que filósofos africanos querem trocar o nome "África" do continente.

›
Kí nìdí tí àwọn onímọ̀ ọgbọ́n orí ní ilẹ̀ Áfíríkà fẹ́ yí orúkọ ilẹ̀ Áfíríkà padà. Por que filósofos africanos querem trocar o nome "Áfr...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.