Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

domingo, 22 de dezembro de 2024

A descoberta de como células cancerígenas "conseguem viver para sempre"

›
Ìkẹ́kọ̀ọ́ ṣípayá bí àwọn sẹ́ẹ̀lì ṣe ‘lè ní ìyè àìnípẹ̀kun’ . Estudo revela como células 'podem ter vida eterna'. Tó o bá fẹ́ ìsọfúnn...
quinta-feira, 7 de novembro de 2024

Método de estudo.

›
 Ìjẹ́pàtàkì ọ̀nà ìkẹ́kọ̀ọ́ tó dára. Importância de um bom método de estudo. Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se você precisar de mais info...
sábado, 26 de outubro de 2024

Números no idioma yorubá

›
  Àwọn nọ́ńbà ní èdè Yorùbá. Números no idioma yorubá. Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se você precisar de mais informações: https://en.w...
segunda-feira, 7 de outubro de 2024

Perguntas aos ateus

›
Ọ̀wọ́ àwọn ìbéèrè kan fún àwọn aláìgbàgbọ́ nínú wíwà Ọlọ́run tí wọ́n ní ẹ̀rí ọkàn láti gbé yẹ̀ wò. Uma série de questões para os ateus consc...
domingo, 6 de outubro de 2024

Você sabia que os dinossauros ainda vivem entre nós? A paleontologia explica!

›
Ṣé o mọ̀ pé àwọn alángbá dánásọ̀ ṣì ń gbé láàárín wa? Ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ nípa àkẹ̀kù egungun àtijọ́ ṣàlàyé!  Você sabia que os dinossauros ainda v...
sábado, 5 de outubro de 2024

Escala de Kardashev

›
Ìwọ̀n ìdàgbàsókè ọgbọ́n-iṣẹ́ ẹ̀rọ tí ìlàjú kan ní. O grau de desenvolvimento tecnológico de uma civilização. Tipo I: Uma civilização capaz d...

Existência

›
Wíwà tá a wà yìí kì í ṣe nǹkan míì ju àlá kúántù kan lásán ní àárín òfo ayérayé. Essa existência que temos nada mais é do que um mero sonho ...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.