Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

domingo, 16 de fevereiro de 2025

Racista

›
Elérò ẹ̀yà-tèmi-lọ̀gá náà jẹ́ ọmọ jòjòló ńlá kan tí kò tíì já lẹ́nu ọmú. O racista é um bebezão que ainda não foi desmamado. Ọ̀wọ́ ọ̀rọ̀ tó ...
terça-feira, 11 de fevereiro de 2025

Donald Trump

›
Ọ̀pọ̀ èèyàn ń jó sí ohùn àwo CD orin inú ọ̀run àpáàdì Ààrẹ Donald Trump. Muitas pessoas dançam ao som do CD de músicas do inferno de Donald ...

Gavião Kyikatejê Futebol Clube

›
  Ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù tí wọ́n ń pè ní Gavião Kyibatejê. Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se você precisar de mais informações: https://www....
sábado, 8 de fevereiro de 2025

Oração de cura

›
Ní orúkọ Yèyé Ìṣẹ̀dá (Àràmàǹdà Obìnrin náà) àti ti àwọn òrìṣà ìbílẹ̀ ilẹ̀ Áfíríkà, mo bẹ̀ ọ́, Ọbaluaiyé, jọ̀ọ́ mú àwọn àrùn wọ̀nyí sínú ibú ...
quinta-feira, 6 de fevereiro de 2025

Físicos negros

›
  Àwọn onímọ̀ físíìsì aláwọ̀ dúdú (físicos negros)   1.  Neilo  Marcos Trinidad, professor do Instituto de Física (IF) da USP 2.  Sonia Guim...
sábado, 1 de fevereiro de 2025

Cognição em Bactérias

›
Ẹ̀rí ọkàn nínú kòkòrò bakitéríà (consciência em Bactérias) Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se você precisar de mais informações: https://...
quinta-feira, 30 de janeiro de 2025

Refutador de ateu

›
Èmi ni abọgibọ̀pẹ̀ kan tó máa ń ta ko àwọn aláìgbọ́ pé Ọlọ́run wà. Sou um animista que refuta ateus.         Olùkọ́ Orlandes Ọ̀wọ́ ọ̀rọ̀ tó ...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.