Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

sexta-feira, 4 de abril de 2025

Maria Cristina

›
Ẹ̀kọ́ nípa iṣẹ́ ìtọ́jú àìsàn ọkàn-àyà (cardiologia) Aláìsàn: Màríà Kristina Déètì (data): 29/04 Àkókò (horário): 11: 00 Àdírẹ́ẹ̀sì (en dereç...
quinta-feira, 3 de abril de 2025

A origem da luz

›
 Tíọ́rì ìbúgbàù ń lá àti bí ìmọ́lẹ̀  ṣ e bẹ̀rẹ̀. Teoria do Big Bang e a origem da luz. 1.  Orírun tàbí bí ìmọ́lẹ̀ ṣe bẹ̀rẹ̀ lórí àgbáálá ayé...

Dia da libertação dos EUA e dos bilionários oprimidos.

›
1. Ọjọ́ tí a dá Orílẹ̀-Èdè Amẹ́ríkà nídè. Dia da libertação dos EUA. Ìjà fún ìdáǹdè Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà táa ni lára lòdì sí àwọn àwọn orílẹ̀...
quinta-feira, 20 de março de 2025

Como fazer um feitiço bíblico?

›
Yáwè Ọlọ́run  kan tí kọ́ wa láti ṣe èèdì Bíbélì. Um Javé Deus que nos ensinou a fazer feitiços bíblicos. Báwo lo ṣe lè ṣe èèdì Bíbélì? - Com...
segunda-feira, 17 de março de 2025

Urologia

›
Lílọ gbàwòsàn (consulta médica). Déètì (data): 24/03 Àkókò (horário): 9: 45 Àdírẹ́ẹ̀sì (endereço):  ilé ìwòsàn kan tí wọ́n ń pè ní  " C...
segunda-feira, 10 de março de 2025

›
 Ìgbìmọ̀ àwọn ẹ̀yà Bushmen ilẹ̀ Gúúsù Áfríkà Conselho San da África do Sul (South African San Council)  Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - S...
sexta-feira, 28 de fevereiro de 2025

Receita Federal

›
Ẹ̀ka Tó Ń Rí sí Gbígba Owó Orí Nílẹ̀ Bràsíl.   Receita Federal do Brasil. Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se você precisar de mais inform...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.