Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

terça-feira, 15 de abril de 2025

Predestinação e livre-arbítrio no conceito yorùbá de pessoa.

›
Àyànmọ́  àti òmìnira ìfẹ́-inú lójú ìwòye àwọn Yorùbá nípa ẹni. Predestinação e livre-arbítrio no conceito yorùbá de pessoa. Tó o bá fẹ́ ìsọf...

Pronúncia

›
Bí wọ́n ṣe ń pe àwọn ọ̀rọ̀ lédè Yorùbá. Como pronunciar palavras em yorubá. Ohùn àti pípè tí mo gbọ́ látẹnu Ọ̀jọ̀gbọ́n Muideen Adekunle Adeg...
segunda-feira, 14 de abril de 2025

O entrelaçamento quântico entre neurônios pode explicar a consciência

›
Ìsomọ́ kúnntìkì láààrin àwọn sẹ́ẹ̀lì iṣan ọpọlọ lè ṣàlàyé ẹ̀rí ọkàn náà. O entrelaçamento quântico entre neurônios pode explicar a consciênc...
domingo, 6 de abril de 2025

Os Yanomami

›
Ẹ̀yà Yanomami: ibi tí wọ́n ti wá, ìtàn wọn, àṣà wọn àti ojú tí wọ́n fi ń wo ayé. Yanomami: origem, história, práticas e visões de mundo. Tó ...
sexta-feira, 4 de abril de 2025

Maria Cristina

›
Ẹ̀kọ́ nípa iṣẹ́ ìtọ́jú àìsàn ọkàn-àyà (cardiologia) Aláìsàn: Màríà Kristina Déètì (data): 29/04 Àkókò (horário): 11: 00 Àdírẹ́ẹ̀sì (en dereç...
quinta-feira, 3 de abril de 2025

A origem da luz

›
 Tíọ́rì ìbúgbàù ń lá àti bí ìmọ́lẹ̀  ṣ e bẹ̀rẹ̀. Teoria do Big Bang e a origem da luz. 1.  Orírun tàbí bí ìmọ́lẹ̀ ṣe bẹ̀rẹ̀ lórí àgbáálá ayé...

Dia da libertação dos EUA e dos bilionários oprimidos.

›
1. Ọjọ́ tí a dá Orílẹ̀-Èdè Amẹ́ríkà nídè. Dia da libertação dos EUA. Ìjà fún ìdáǹdè Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà táa ni lára lòdì sí àwọn àwọn orílẹ̀...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.