Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

terça-feira, 17 de junho de 2025

Parditude

›
 Ànímọ́ tàbí ipò ẹlẹ́yàpúpọ̀. Característica ou condição de pardo.  Ọ̀wọ́ ọ̀rọ̀ tó wà nínú èdè, àwọn ọ̀rọ̀ tó máa lò, àkójọ ọ̀rọ̀ tí ò ń lò ...
sexta-feira, 6 de junho de 2025

Ramos da quìmica

›
 Àwọn ẹ̀ka kẹ́místrì (ramos da química):  1. Kẹ́místrì onífísíksì - A físico-química : kìnẹ́tíkì kẹ́míkà (cinética química), físíksì kẹ́míkà...
terça-feira, 3 de junho de 2025

Celebração do Dia Nacional do Vodum

›
Àjọ̀dún  Ọjọ́ Torílẹ̀-èdè  Vodun . Festival do Dia Nacional do Vodum. Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Bẹ̀nẹ̀ (República do Benim) No Benim, A reli...
segunda-feira, 2 de junho de 2025

Revoluções tecnológicas

›
Àwọn àyípadà tó wáyé nínú ìmọ̀ ẹ̀rọ. Revoluções tecnológicas. 1.   Ìlò ẹ̀rọ gbọ̀rẹ̀gẹ̀jigẹ̀ (m ecanização). 2. Ìlò iná mànàmáná (e letrifica...
sábado, 31 de maio de 2025

O pau que nasce torto, morre torto.

›
Wíwọ́ ni igi tí ó hù ní wíwọ́ yóò wọ́ títí yóò fi kú  O pau que nasce torto, morre torto. Ọ̀wọ́ ọ̀rọ̀ tó wà nín ú èdè, àwọn ọ̀rọ̀ tó máa lò,...
sexta-feira, 30 de maio de 2025

História reversa

›
    Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ wọ̀nyí wáyé nítòótọ́, àní gẹ́gẹ́ bí àwọn òpìtàn bíi John Glover Jackson pàápàá ti fìdí rẹ̀ múlẹ̀. Esses eventos realmente a...
domingo, 25 de maio de 2025

Apoio do povo

›
Rántí pé Nérò Olú Ọba Róòmù ti dáná sun ìlú Róòmù nítorí pé ó ní ìtìlẹyìn àwọn èèyàn. Lembre-se de que o imperador romano Nero queimou a cid...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.