Aulas de yorùbá: Olùkọ́ Orlandes

Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.

sábado, 2 de agosto de 2025

Plural de cores

›
  1.  Àwọn àwọ̀ nínú èdè Yorùbá (as cores na língua yorubá):    - Àwọn àwọ̀ àkọ́kọ́ (cores primárias):   àwọ̀ dúdú (cor preta), àwọ̀ pupa (c...
quinta-feira, 31 de julho de 2025

Concurso

›
Ìbéèrè tó jẹ mọ́ ìdánwò gbogbogbòò (questão de concurso).  Qual alternativa apresenta apenas um plural? A) Corrimão (corrimãos, corrimões). ...
quarta-feira, 23 de julho de 2025

Ideogramas chineses

›
Àwọn lẹ́tà èdè Ṣáínà náà. Ideogramas chineses. O escriba Cāng Jié (organizador dos ideogramas chineses) viveu na época do imperador amarelo ...
sábado, 12 de julho de 2025

Sociedade Protetora dos Desvalidos.

›
  Àjọ Tó máa ń dáàbò bo Àwọn tí kò lólùrànlọ́wọ́. Sociedade Protetora dos Desvalidos. Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se você precisar d...

Glossário kemético (àlàyé ọ̀rọ̀ inú èdè Kẹ́mẹ́ẹ̀tì)

›
Àlàyé ọ̀rọ̀ tó wà lédè àwọn ará Yorùbá àti tàwọn ará Íjíbítì ìgbàanì . Glossário bilíngue, em yorubá e egípcio antigo.   Ilẹ̀ Kẹ́mẹ́ẹ̀tì, Kẹ...
quarta-feira, 9 de julho de 2025

Luta pela nossa libertação

›
Ìjà láti wá ìtúsílẹ̀ fún wa. Luta pela nossa libertação. Ìgbésẹ̀ mẹ́ta (três etapas):    1. Ìsọdibiàmúsìn: colonialismo. 2. Ìsọdòmìnira : in...
terça-feira, 8 de julho de 2025

Deus-sol (Deus-sol).

›
Ọlọ́run oòrùn kan tó sọ ara rẹ̀ di onírúurú ohun alààyè. Um Deus-sol que se autotransformou em todos os tipos de seres vivos. 1. Na mitologi...
‹
›
Página inicial
Ver versão para a web

AULAS DE YORÙBÁ

Minha foto
Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias
Mo lálàá pé lọ́jọ́ kan, a óò lè rán sí àgbáyé, nípasẹ̀ àwọn sátẹ́láìtì àti orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, èdè yorùbá, ẹ̀sìn òrìṣà, fúdù, iṣẹ́ àjẹ́, idán pípa, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, tẹknọ́lọ́jì, sáyẹ́nsì, àti físíksì kùátọ̀mù - Sonho que um dia possamos enviar para o mundo, via satélites e Internet, a língua iorubá, religião de Orixá, macumba, feitiçaria, magia, filosofia, tecnologia, ciência e física quântica.
Ver meu perfil completo
Tecnologia do Blogger.