Sé o lo sójjà?
Será que você foi ao mercado?
Rárá, nkò lo sójà
Não, não fui ao mercado.
Béèni, mo lo sójà.
Sim, eu fui ao mercado.
Sé Délé ni òré Túnjí?
Será que Délé é amigo de Túnjí?
Béèni, Délé ni òré Túnjí.
Sim, Délé é amigo de Túnjí.
Rárá, Délé kó ni òré Túnjí.
Não, Délé não é amigo de Túnjí.
Glossário:
Sé = será que?
Ni = é, ser.
O = Você.
Lo = ir.
Sí = contra, para, em ( Sempre usado com verbo que indica um movimento direcional).
Ojà = mercado.
Kó ni= não é
Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.