Àjẹmọ́nú Ìwọ̀ Oòrùn ayé (gratificação faroeste).
Rio aprova “gratificação faroeste”, que premia policial que promove genocídio de pessoas pretas nas favelas.
Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se você precisar de mais informações:
https://ponte.org/artigo-gratificacao-faroeste-e-a-ampliacao-do-genocidio-nas-favelas/
https://dmjracial.com/2023/06/21/a-nova-versao-da-gratificacao-faroeste/
Ọ̀wọ́ ọ̀rọ̀ tó wà nínú èdè, àwọn ọ̀rọ̀ tó máa lò, àkójọ ọ̀rọ̀ tí ò ń lò lójoojúmọ́, àwọn àkànlò ọ̀rọ̀, àwọn àkànlò èdè, ọ̀rọ̀ tó máa ń sọ, àkànlò èdè lọ́nà tó gún régé (vocabulário).
Nwọ́n, pron. pess. Eles, elas. Expressa uma ação que não é creditada a nenhuma pessoa em particular.
Àwọn, wọ́n, pron. Eles, elas. É também usado como partícula para formar o plural do substantivo; neste caso, é posicionado antes do substantivo.
Wọn, pron. oblíquo. A eles, a elas.
Wọn, pron. poss. Deles, delas.
Ayẹyẹ, s. Celebração.
Àjọ̀dún, s. Festival.
Ìwọ̀ Oòrùn ayé, s. Oeste do mundo.
Àwọn sinimá Ìwọ̀ Oòrùn ayé, s. Filmes de faroeste.
Àjẹmọ́nú Ìwọ̀ Oòrùn ayé, s. Gratificação faroeste.
Àjẹmọ́nú, s. Bônus, gratificação.
Àwọn ẹ̀bùn owó, s. Gorjetas, prêmios em dinheiro.
Ayẹyẹ kan tí wọ́n ti fẹ́ pín ẹ̀bùn fún àwọn ọmọléèwé, s. Uma cerimônia de premiação na escola.
Ayẹyẹ ìfúnnilẹ́bùn, s. Cerimônia de premiação.
Àwọn ẹbun ìdálọ́lá, s. Premiações, prêmios de honra.
Ayẹyẹ ìfúnnilẹ́bùn ti ọdọọdún fún ẹgbẹ́ afigigbábọ́ọ̀lù ẹlẹ́ni mọ́kànlá ti àwọn obìnrin, s. Premiação anual da equipe feminina de críquete.
Iṣẹ́ àfipawọ́, s. Trabalho estra.
Àwọn ọjà títà, v. Vendas.
Ogun abẹ́lé, s. Guerra civil.
Àwọn ọlọ́pàá aráàlú, àwọn ọlọ́pàá abẹ́lé, s. Polícia civil.
Ìpẹ̀yàrun, pípa ẹ̀yà run, ìpalápalù ẹ̀yà, ìpalápatán ẹ̀yà, ìpakúpa, ìpakúpa-ẹ̀yà, ìparun ẹ̀yà, pípa ẹ̀yà ìran kan run, ìpanírun, s. Genocídio. Trata-se de genocídio nas três acepções do Dicionário Houaiss -- de acordo com o entendimento que tem o Tribunal Penal Internacional: "1.1) extermínio deliberado, parcial ou total, de uma comunidade, grupo étnico, racial ou religioso"; "1.2) por extensão, destruição de populações ou povos"; "1.3) aniquilamento de grupos humanos, o qual, sem chegar ao assassínio em massa, inclui outras formas de extermínio, como a prevenção de nascimentos, o sequestro sistemático de crianças dentro de um determinado grupo étnico, a submissão a condições insuportáveis de vida etc"
Ìpakúpa, s. Massacre.
Ìpakúpa rẹpẹtẹ náà, s. O holocausto.
Ìparun ẹ̀yà, s. Limpeza étnica.
Pípa ẹ̀yà ìran run, pípa ìran run, pípa odindi ẹ̀yà run, s. Limpeza étnica, genocídio.
Ìṣìkàpa ọ̀pọ̀ rẹpẹtẹ àwọn aráàlú, s. Massacre de civis.
Ìpẹ̀yà ìran èèyàn dúdú run, ìparun ẹ̀yà ìran èèyàn dúdú, ìparun ẹ̀yà ìran ènìyàn dúdú, s. Maafa (holocausto africano, holocausto da escravidão ou holocausto negro).
Ìpakúpa ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn, s. Massacre de muitas pessoas.
Pípa, s. Ato de matar, matança.
Ìtàjẹ̀, ìtàjẹ̀sílẹ̀, s. Matança, derramamento de sangue.
Pípa ẹ̀yà ìran Yanomami run tí ó wáyé ní Bràsíl nígbà ìṣàkóso ààrẹ Bolsonaro, s. Genocídio da etnia Yanomami ocorrido no Brasil durante o governo do presidente Bolsonaro.
Ìpẹ̀yàrun tó wáyé lábẹ́ ìjọba Stalin ní ilẹ̀ Estóníà, s. Genocídio estoniano sob regime estalinista.
Ìpalápatán ẹ̀yà ti Tutsi àti Hutu tí wọ́n ń gbé ní Rùwándà, s. Genocídio de Tutsi e Hutu que vivem em Ruanda.
Pípa ẹ̀yà run, s. Genocídio em massa.
Ìparun ẹ̀yà àwọn ará adúláwọ̀ àti àmẹ́ríńdíà tí wọ́n ń gbé ní Bràsíl, s. Genocídio de negros e ameríndios que vivem no Brasil.
Ìpẹ̀yàrun tí wọ́n máa ń díbọ́n bí ogun tó ja àwọn oògùn olóró, s. Genocídio disfarçado de guerra às drogas.
Ìparun ẹ̀yà àwọn ará Arméníà, s. Genocídio do povo armênio.
Ìparun ẹ̀yà àwọn ará adúláwọ̀, s. Maafa, genocídio do povo negro, holocausto africano.
Ìparun ẹ̀yà tí ó wáyé ní Rùwándà, s. Genocídio em Ruanda.
Ìṣìkàpa ọ̀pọ̀ rẹpẹtẹ àwọn aráàlú láti ọwọ́ àwọn ìjọba tiwọn fúnra wọn, s. Genocídios de seus cidadãos praticados pelos governos.
Ìpẹ̀yàrun tó wáyé ní Kàmbódíà, s. Genocídio no Camboja
Ìparun ẹ̀yà náà ní àwọn àgọ́ ìṣẹ́niníṣẹ̀ẹ́ násì, s. Genocídio nos campos de concentração nazistas.
Ìpẹ̀yàrun tó wáyé lábẹ́ ìjọba Bẹnjamínì Nétáníhámù ní ilẹ̀ Palẹ́sìnì, s. Genocídio ocorrido sob o governo de Benjamin Netanyahu na Palestina.