quarta-feira, 12 de dezembro de 2018

Ètò ẹ̀sọ ara

Ètò ẹ̀sọ ara - O sistema nervoso.




.
Ẹ̀sọ (nervo).
Ètò ẹ̀sọ t’ogangan (sistema nervoso central).  
Pádi ẹ̀sọ (célula nervosa , neurônio ). 
Ètò ẹ̀sọ t’àgbèègbè (sistema nervoso periférico). 
Ìṣù ẹ̀sọ (cordão do nervo).
Ọ̀ran ẹ̀sọ (fibra nervosa).
Ọ̀pá ẹhìn (coluna vertebral).
Irìn ẹ̀sọ (raiz nervosa).
Ẹ̀kọ́ ẹ̀sọ (neurologia).
Ihò ọ̀pá-ẹhìn (canal espinhal).
Oníṣègùn ẹ̀sọ-ara (neurologista). 
Ọ̀pọlọ (cérebro).
Irun ẹ̀sọ (dendritos do neurônio).
Ẹ̀sọ ọ̀pá-ẹhìn (medula espinhal).
Ẹ̀sọ ìmira (nervo motor).
Ẹ̀sọ atọ̀páyọ (nervo espinhal).
Àwọn ẹ̀sọ-iyè (nervos sensoriais). 
Pádi ẹ̀sọ-ìmira (neurônio motor).
Ẹ̀sọ adáṣiṣẹ́ (nervo autônomo, neurônio). 
Pádi ẹ̀sọ-ìmira (neurônio motor).
Ẹ̀sọ iyè-ìríran (nervo óptico).
Ẹ̀sọ iyè (nervo sensitivo).
Ẹ̀sọ ìgbọrọ (nervo acústico).
Ẹ̀sọ atọ̀páyọ (nervo espinhal).
Ẹ̀sọ akọkàn (fibra nervosa aferente, nervo aferente). 
Ẹ̀sọ afún-ìṣọ̀n (nervo vasoconstritor). 
Ẹ̀sọ atoríyọ (nervo craniano), 
Ẹ̀sọ aṣọ-ìṣọ̀n (nervo vasodilatador), 
Ẹ̀sọ ìmira (fibra nervosa eferente, nervo eferente). 
Ẹ̀sọ ìmira-ìṣọ̀n (nervo vasomotor). 
Ẹ̀sọ iyè-òórùn (nervo olfatório).
Ẹ̀sọ ìmira-ojú (nervo oftálmico).
Ẹ̀sọ ẹṣẹ́-ara (nervo secretor).
Pádi ẹ̀sọ-ìmira (neurônio motor).