sexta-feira, 11 de setembro de 2015

Pedido


Kọ ọ̀rọ̀ nípa ara rẹ, kí o sì tẹ Jọ̀wọ́ Kàn sí Mi láti fi í ránṣẹ́.
-Insira suas informações e clique no botão Enviar pedido.
-Escreva sua própria mensagem, e entre em contato comigo para enviar.




1. Sọ nípa ara rẹ (Conte mais a seu respeito).

Orúkọ àkọ́kọ́ (Primeiro nome)

Orúkọ ìdílé (Último nome)

Èwo lo jẹ́ (sexo)
( ) Ọkùnrin (masculino)  ( ) Obìnrin (Feminino)
Èdè Tí Mo Fẹ́ (Idioma de preferência)


2. Báwo la ṣe lè kàn sí ẹ? (Como podemos contatar você?)

Orílẹ̀-Èdè (País)


Àdírẹ́sì 1 (Endereço 1)

Àdírẹ́sì 2(Tó bá wù ẹ́) - Endereço 2(Opcional)


Àdírẹ́sì 3(Tó bá wù ẹ́) - Endereço 2(Opcional)

Àdúgbò(Tó bá wù ẹ́) - Comunidade(Opcional)

Ìlú (cidade)

Ìpínlẹ̀ (Estado, província)

Nọ́ńbà Tó O Fi Ń Gba Lẹ́tà(Tó bá wù ẹ́) - Código postal(Opcional)

Ext.(Tó bá wù ẹ́) - Ext.(Opcional)

Tẹlifóònù(Tó bá wù ẹ́) - Telefone(Opcional)  

Ìgbà Tá A Lè Bá Ẹ Nílé(Tó bá wù ẹ́) - Melhor hora para contatar você (Opcional)

Òwúrọ̀ (manhã)


Jọ̀wọ́ Kàn sí Mi (Enviar pedido)
Resultado de imagem para Botão de enviar pedido

Religião

 Ìsìn Krístíánì Kátólìkì  nínú  ilé Kandomblé - Tẹlifíṣàn yorùbá.
Missa Católica dentro da Casa de Candomblé - Tv Yoruba.
                                                     

Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário).


Ẹ̀sìn, s. Religião.
Ìsìn Krístíánì, s. Missa.
Ilé, s. Casa.
Baháí, s. Fé bahá'í
Kandomblé, s. Candomblé.
Santería, s. Santeria
Shinto, ẹ̀sìn ìbílẹ̀ Japan, s. Xintoísmo.
Ọlọ́run, s. Deus supremo.
Kríslàm, s. Crislã. Sincretismo do cristianismo com o islã.
Ìṣeìjọkríslàm, ìṣekríslàm, ìṣekrísmàle, ìṣeìjọkrísmàle, ẹ̀sìn Krístì-ìmàle, s. Crislamismo. Sincretismo do cristianismo com o islã.
Ṣọ́ọ̀ṣì Kátólíìkì, ìjọ Kátólìkì, s. Igreja católica.
Ṣọ́ọ̀ṣì Ọ́tọ́dọ́ọ̀sì ti Ìlà Oòrùn , s. Igreja ortodoxa oriental.
Ìwé Àpókírífà, s. Livros apócrifos.
Ẹ̀sìn Krístì, s. Cristianismo.
Ìṣeìjọánglíkánì, s. Anglicanismo.
Ìjọ ilẹ̀ Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì, s. Igreja Anglicana. 
Ìjọ Jéésù Lótìítọ́, s. Verdadeira Igreja de Jesus.
Mósè, s. Moisés.
Màríà (ìyá Jésù), s. Maria (mãe de Jesus).
Jésù Krístì, s. Jesus Cristo.
Bíbélì Mímọ́, s. Bíblia sagrada.
Ónjẹ Alẹ́ Olúwa, s. Última ceia.
Òfin Mẹ́wàá, s. Dez Mandamentos, decálogo.
Ìṣeìjọpurẹsibiteriani, s. Presbiterianismo.
Purẹsibiteriani, adj. Presbiteriano. Protestante que não reconhece a autoridade episcopal e nem aceita hierarquia superior à dos presbíteros.
Ìjọ Purẹsibiteriani, s. Igreja presbiteriana.
Ìmàle‎, s. Islamismo.
Ìṣebúddhà‎, s. Budismo.
Ìṣehíndù‎, ẹ̀sìn-ìn Híndùs. Hinduísmo.
Ẹ̀sìn Ọlọ́runkan, s. Religião monoteísta.
Ẹ̀sìn Ọlọ́runpúpọ̀, s. Religião politeísta.
Ẹlẹ́sìn Pùròtẹ́sítáǹtì, s. Protestante.