Àwọn àwòṣe méjìlá (doze arquétipos).
Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se você precisar de mais informações:
https://www.reinodexango.com.br/arquetipos-dos-orixas/
https://www.douglasmaluf.com.br/os-12-arquetipos-de-jung-qual-e-o-seu/
1. Aláìṣẹ̀, aláìmọwọ́-mẹsẹ̀ (o inocente).
2. Ọlọ́gbọ́n (o sábio).
3. Olùdágbáléwu, olùṣàyẹ̀wòkiri, aṣàwákiri (o aventureiro, o explorador).
4. Ọlọ̀tẹ̀ (o rebelde).
5. Onídán, àlùfáà onídán, àlùfáà pidánpidán (o mago).
6. Akọni (o herói).
7. Olùfẹ́ (o amante).
8. Apanilẹ́rin, aláwàdà (o comediante).
9. Ọmọ tó jẹ́ ti àwọn ará ìlú, èèyàn bíi tiwa, èèyàn lásánlàsàn (pessoa comum, pessoa como nós, o comum)
10. Olùṣètọ́jú (o cuidador).
11. Alákòóso (o governante).
12. Ẹlẹ́dàá (o criador).
Àwọn ọ̀rọ̀-orúkọ tó tan mọ́ ọn - Substantivos relacionados: aláàánú (misericordioso), agbẹ̀mílà (salvador, socorrista), aláìmọtara-ẹni (altruísta), aládùúgbò rere (o bom vizinho), ẹni rírẹlẹ̀ (o humilde), agbatẹniro (o prestativo), apanirun (o destridor), ajàjàgbara (revolucionário), ẹni tó fẹ́ gbàjọba (rebelde) agbábẹ́lẹ̀jagun (guerrilheiro), gómìnà (governador), kàlífà, olórí (califa), séríkí (xeque, xeique, sheik), olú ọba (imperador), ọba (xá, czar, rei, monarca), sọ́táànì (sultão), ẹ́míà (emir), ààrẹ (presidente), alákòóso àgbà (primeiro-ministro), pópù (papa).