Ìwádìí nípa àwọn ohun tó wà lójú ọ̀run (cosmologia).
Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀ (Vocabulário).
Ohun tó jẹ́ èrò, s. Ponto de vista.
Wíwò nípa àgbáyé, s. Visão de mundo.
Ìtòràwọ̀, s. Astronomia.
Físíksìoníràwọ̀, s. Astrofísica.
Wíwo ìràwọ̀, ìwòràwọ̀, s. Astrologia.
Wíwò ayé, wiwò nípa ayé, wiwò nípa ayé náà, s. Cosmovisão.
Ọ̀rọ̀-ìgbéayé, ìwádìí nípa àwọn ohun tó wà lójú ọ̀run, s. Cosmologia.