segunda-feira, 9 de maio de 2022

- Afropaty

Obìnrin dúdú kan tí ó jẹ́ ọlọ́rọ̀ tó sábà máa ń wọ àwọn aṣọ ìgbàlódé.

Uma preta rica que costuma usar roupas de grife (afropatypreta patrícia).


https://mobile.facebook.com/story.php?story_fbid=394971869037873&id=102677458267317&_rdc=1&_rdr

Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se você precisar de mais informações:

https://marciatravessoni.com.br/entretenimento/o-que-significa-ser-uma-afropaty-ou-preta-patricia/

Ọ̀wọ́ ọ̀rọ̀ tó wà nínú èdè, àwọn ọ̀rọ̀ tó máa lò, àkójọ ọ̀rọ̀ tí ò ń lò lójoojúmọ́, àwọn àkànlò ọ̀rọ̀, àwọn àkànlò èdè, ọ̀rọ̀ tó máa ń sọ, àkànlò èdè lọ́nà tó gún régé (vocabulário).

Nwọ́n, pron. pess. Eles, elas. Expressa uma ação que não é creditada a nenhuma pessoa em particular.

Àwọn, wọ́n, pron. Eles, elas. É também usado como partícula para formar o plural do substantivo; neste caso, é posicionado antes do substantivo.

Wọn, pron. oblíquo. A eles, a elas.

Wọn, pron. poss. Deles, delas.

Obìnrin ọlọ́rọ̀, s. Mulher rica.

Obìnrin dúdú kan tí ó jẹ́ ọlọ́rọ̀, s. Uma preta rica.

Obìnrin ọlọ́rọ̀ kan tó sábà máa ń wọ aṣọ ìgbàlódé, s. Patrioinha. Uma mulher rica que usa roupa de grife.

Obìnrin ọlọ́rọ̀ kan tó máa ń wọ aṣọ olówó-ńlá tàbí ohun-ọ̀ṣọ́ dídán yanranyanran, s. Patrioinha. Uma mulher rica que usa roupas caras ou joias brilhantes.

Obìnrin ọlọ́rọ̀ kan tó máa ń wọ aṣọ tó dáa gan-an, s. Patrioinha. Uma mulher rica que usa roupa magnífica.

Ọmọbìnrin bàbá olówó kan tó sábà máa ń wọ àwọn aṣọ ìgbàlódé, s. Patricinha. A filha de um pai rico que costuma usar roupas de grife.

Ọ̀dọ́bìnrin ọlọ́rọ̀ kan tí àwọn òbí rẹ̀ máa ń ra àwọn aṣọ ìgbàlódé fún un, s. Patricinha. Uma jovem rica cujos pais compram roupas de grife para ela.

Ọ̀dọ́bìnrin dúdú kan tí ó jẹ́ ọlọ́rọ̀ tí àwọn òbí rẹ̀ máa ń ra àwọn aṣọ ìgbàlódé fún un, s. Petricinha. Uma patricinha preta cujos pais compram roupas de grife para ela.


- Mercadorias (àwọn ọjà)

Àwọn ohun ọ̀ṣọ́ ilé, ohun-èlò, ẹ̀rọ tí a ń lò nínú ilé àti ohun abánáṣiṣẹ́.

Móveis, utensílios, eletrodomésticos e equipamentos eletrônicos.

Ọ̀wọ́ ọ̀rọ̀ tó wà nínú èdè, àwọn ọ̀rọ̀ tó máa lò, àkójọ ọ̀rọ̀ tí ò ń lò lójoojúmọ́, àwọn àkànlò ọ̀rọ̀, àwọn àkànlò èdè, ọ̀rọ̀ tó máa ń sọ, àkànlò èdè lọ́nà tó gún régé (vocabulário).


Nwọ́n, pron. pess. Eles, elas. Expressa uma ação que não é creditada a nenhuma pessoa em particular.

Àwọn, wọ́n, pron. Eles, elas. É também usado como partícula para formar o plural do substantivo; neste caso, é posicionado antes do substantivo.

Wọn, pron. oblíquo. A eles, a elas.

Wọn, pron. poss. Deles, delas.

Tábìlì, s. Mesa.

Àga, s. Cadeira.

Àpótí ìjókòó, s. Banco.

Àpótí ẹrù, s. Baú. 

Kọ́bọ́ọ̀dù, kọ́bọ́dù, s. Armário.

Kámẹ́rà, s. Câmera. 

Àwọn kámẹ́rà àti gọgọwú tẹlifíṣọ̀n aríléróde abẹ́lé, s. Câmeras e monitores de circuitos fechados de TV.

Tẹlifíṣọ̀n, s. Televisão.

Rédíò, s. Rádio.

Fóònù alágbèéká, s. Celular, telefone celular.

Kọ̀ǹpútà alágbèéká, s. Notebook.

Kọ̀mpútà, s. Computador.

Fóònù tó lágbára, fóònù ìgbàlódé, s.  Smartphone.

Tẹlifóònù, s. Telefone.

Ohun tí wọ́n fi ń gbọ́ orín bọ etí, ẹ̀rọ tí wọ́n fi ń gbọ́ orin sétí, s. Fone de ouvido, um dispositivo para ouvir música.

Àwọn ìhùmọ̀ ìgbọ́ròó láti túbọ̀ mú kí ìwọ̀n agbára ìgbọ́rò, s. Aparelhos auditivos para maximizar a audição, aparelhos auditivos para ampliar qualquer audição residual. 

Ẹ̀rọ ńlá tí mo fi ń gbọ́ràn sí, s. Enorme aparelho de audição.

Ìhùmọ̀ ìgbọ́ròó, s. Aparelho auditivo.

Àwọn ohun agbọ́rọ̀jáde ti a ń gbékọ́ etí fún àwọn tí ó lekoko fún láti gbọ́rọ̀, s. Fones de ouvido para os que têm dificuldade de ouvir.

Rédíò alágbèéká kan tí ó ní ẹ̀rọ amúnáwá, aláfọwọ́yí, tí a ṣe mọ́ ọn, s. Um rádio portátil com um gerador manual embutido.

Rédíò kékeré kan tó ní bátìrì tuntun, s. Um pequeno rádio com uma bateria nova.

Rédíò alágbèéká, s. Rádio portátil.

Ẹ̀rọ ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́, ẹ̀rọ gbohùngbohùn, s. Caixa de som, alto-falante.

Búrọ́ọ̀ṣì, s. Escova.

Búrọ́ọ̀ṣì kan ti a fi ń gbẹ irun, s. Escova secadora.

Ẹ̀rọ ìgbẹrun, s. Secador de cabelos.

Ẹ̀rọ ti a fi ń gbẹ aṣọ, s. Secador.

Ẹ̀rọ tó mú irun orí tọ́, s. Alisador de cabelo, chapa alisadora. 

Ẹ̀rọ ìlọǹkan, s. Liquidificador.

Ìfúntí, s. Espremedor de frutas para o fabrico de vinho.

Ẹ̀rọ tó lè yọ omi èso jáde, s. Extrator de suco de frutas.

Àwọn ẹ̀rọ ìpoǹkanpọ̀ oníná, s. Batedeiras.

Àwọn ẹ̀rọ ìgbọ́únjẹ, s. Processadores de alimentos. 
Àwọn ohun èlò tá a fi ń se oúnjẹ, s. Utensílios de cozinha.
Ohun èlò tó ń lo iná mànàmáná, s. Panela elétrica.
Ìkòkò, s. Pote, vasilha.
Ìkòkò ìse-oúnjẹ, s. Panela. 
Ohun-èèlò tàbí ìṣàgbékalẹ̀ láti yan ẹran tí wọ́n máa jẹ, ohun-èèlò tàbí ìṣàgbékalẹ̀ tá a lò láti yan ẹran, s. Utensílio ou instalação para assar carne para comer, churrasqueira.
Ẹ̀rọ tí a ń lò nínú ilé tá a lò láti dẹ́ran àti àwọn ohun jíjẹ mìíràn, s. Eletrodoméstico usado para fritar carne e outros alimentos, fritadeira. 
Ẹ̀rọ ìtẹ̀wé oníná, s. Impressora elétrica.
Ẹ̀rọ ìtẹ̀wé alátẹ̀yípo ńlá, s. Grande impressora rotativa.
Ẹ̀rọ ìfọṣọ, s. Máquina de lavar. 
Ẹ̀rọ kan tó máa ń ya nǹkan sọ́tọ̀ọ̀tọ̀, s. Centrífuga.
Ẹ̀rọ kan tí yóò fi agbára fún oyin jáde, s. Uma centrífuga que extrai o mel.
Ẹ̀rọ ìṣaǹkan tí ń yí bírí láti yọ àwọn èèpo kúrò àti láti mú kí agbára òróró tajútajú náà pọ̀ sí i, s. Centrífuga para remover a casca e para aumentar a concentração de óleo volátil.
Táǹkì, s. Tanque.
Ààrò tí wọ́n ti ń dáná igi, s. Fogão a lenha.
Àdìrò, ààrò, ẹ̀rọ ìdáná, s. Lareira, forno. 
Ẹ̀rọ amú-nǹkan-gbóná tí wọ́n ń pè ní microvave, s. Forno de micro-ondas.
Àrò, ẹ̀rọ ìdáná, s. Forno, fogão, estufa, fornalha. Sítóòfù (do inglês stove), s. Fogão.
Àdìrò tó ń lo iná mànàmáná, s. Forno elétrico.
Ihò omi kan, ibi kòtò olómi, ẹ̀rọ omi, s. Bebedouro.
Ẹ̀rọ tó máa ń fọ omi mọ́, s. Purificador de água.
Fìríìjì, s. Freezer.
Ẹ̀rọ̀ amú-nǹkan-tutù, ẹ̀rọ amúǹkantutù, ẹ̀rọ tí ń mú ǹkan tutù, ẹ̀rọ amómitutù, fìríìjì, s. Geladeira, refrigerador.
Àga tó fẹ́ràn jù, s. Cadeira favorita, sofá.
Ìjókòó gbọọrọ onítìmùtìmù, s.  Uma cadeira reclinável confortável, sofá.
Àga ìrọ̀gbọ̀kú, àga ìgbafàájì, s. Cadeira. reclinável, sofá.
Àga ìnàyìn, s. Sofá.
Àga onítìmùtìmù, s. Estofado.
Kọ́tìnì, s. Cortina.
Ilé ìtajà ńlá kan, s. Uma grande loja.
Pẹpẹ ìkówèésí, pẹpẹ-ìwé, pẹpẹ ìkẹ́rùsí, pẹpẹ, s. Prateleira.
Pẹpẹ, s. Prateleira, estante, altar.
Àwọn àpótí ìkówèésí, s. Prateleiras de livros.
Pánẹ́ẹ̀lì tó ń lọ fún tẹlifíṣọ̀n, s. Painel para 
TV.
Àwọn pẹpẹ onígíláàsì, s. Balcões de vidro.
Káńtà, s. Balcão.
Ibi ìkówèésí, pẹpẹ ìkówèésí, pẹpẹ-ìwé, s. Estante para livros.
Àwọn àgbékọ́ amáraró, s.  Suportes para os pés.
Orí-ikọ́, oríkọ́, s. Anzol, colchete, gancho. 
Ìgangan, s. Cabide. Um tipo de peixe.
Ibi ìkáṣọsí,  àpótí aṣọ, s. Guarda-roupa, roupeiro. 
Bẹ́ẹ̀dì, ibùsùn, s. Cama.
Bẹ́ẹ̀dì ọmọ ọwọ́, s. Cama de bebê, berço.
Bẹ́ẹ̀dì alágbèékà, s. Beliche.
Bẹ́ẹ̀dì tó bá ọmọdé mu, bẹ́ẹ̀dì fún ọmọdé, s. Cama infantil.
Mátírẹ́ẹ̀sì, s. Colchão.
Mátírẹ́ẹ̀sì tó jẹ́ pé aṣọ tí wọ́n fi ṣe é kì í gbọn ìdọ̀tí tín-íntìn-ìntín, s.  Colchão de fibras sintéticas.
Mátírẹ́ẹ̀sì oníkoríko tí wọ́n fi ẹní bò, s. Colchão de palha, coberto por esteira.
Mátírẹ́ẹ̀sì oníkoríko, s. Colchão de palha.
Àpótí ìkọ̀wé, s. Escrivaninha.
Kọ́bọ́ọ̀dù kan tó ní ọ̀pọ̀lọpọ̀  ibi-ìkó-nǹkan-sí , s. Um armário que tem várias gavetas, cômoda. 
Àpótí ìkó-ǹkan-sí tuntun sí ilé ìdáná, àpótí ìkó-ǹkan-sí tuntun sí kíṣìnnì, s. Novo armário de cozinha.
Tábìlì onígi, s. Mesa de madeira. 
Tábìlì onígíláàsì, s. Mesa de vidro. 
Tábìlì tí wọ́n fi òkúta mábù ṣe, s. Mesa de mármore.
Tábìlì tí a fi akọ òkúta ṣe, s. Mesa de granito.
Tábìlì tí a fi rúbì ṣe, s. Mesa de rubi.
Káńtà tá à ń lò nínú kíṣìnnì, s. Balcão usado na cozinha, balcão de cozinha.
Àkójọ ọ̀bẹ, àpapọ̀ àwọn ọ̀bẹ, s. Jogo de facas. 
Àkọ̀ tàbí àpótí tá a lò láti fi àwọn fọ́elétricaọ̀kì, ṣíbí àti ọ̀bẹ sínú rẹ̀, s. Um estojo ou caixa usado para guardar garfos, colheres e facas dentro dele, faqueiro.
Àgé, s. Vasilha para apanhar água, chaleira.
Àgé tó ń lo iná mànàmáná, s. Chaleira elétrica.

Ohun èlò ìsekọfí, ohun tí a fi ń ṣe kọfí, s. Cafeteira.

Ife ìmukọfí, s. Xícara de café.

Ohun-èlò tàbí ẹ̀rọ nínú èyìtí a gbé àwọn ọmọ àgbàdo láti ṣe gúgúrú, s. Vasilha ou máquina em que se colocam grãos de milho para fazer pipocas, pipoqueira. 

Ààrò oníná tá a lè yan búrẹ́dì, ààrò oníná tí a fi ń yan búrẹ́dì sílẹ̀, s. Torradeira de pão. 

Àwọn àwo oúnjẹ tí wọ́n fi fàdákà àti àwọn mẹ́táàlì ṣíṣeyebíye mìíràn ṣe, s. Aparelhos de jantar de prata e de outros metais preciosos.

Àwọn abọ́ ìmumi, s. Cálices.

Àwọn àwo, s. Pratos. 

Àwọn ife, s. Copos.

Ẹ̀rọ kan tó lè fi omi díẹ̀ sí i sí àyíká rẹ nínú ìyàrá kan, s. Um dispositivo que pode umedecer seu ambiente dentro de uma sala, umidificador.

Òṣùwọ̀n tí ń díwọ̀n ariwo ní ìwọ̀n decibel, s. Medidor de som em decibéis.

Òṣùwọ̀n onídíjítà kan tó máa ń wọn ìwọ̀n ìfúnpá, òṣùwọ̀n onídíjítà kan tó máa ń wọn ẹ̀jẹ̀ ríru, s. Um monitor digital que mede a pressão arterial, um medidor de pressão digital, um monitor digital de pressão.

Àwọn oògùn tó máa ń fà símú, s. Inaladores. 

Òṣùwọ̀n onídíjítà, s. Balança digital. 

Òṣùwọ̀n tó péye, s.  Balança exata.

Ẹ̀rọ tó lo oruku omi láti lọ aṣọ, ẹ̀rọ tó lò  kùrukùru omi láti lọ aṣọ, s. Ferro a vapor.

Ẹ̀rọ ìlọṣọ, ẹ̀rọ tí a fi ń lọ aṣọ, s. Ferro de passar roupa.

Ẹ̀rọ abánáṣiṣẹ́ kan tó lo oruku omi láti lọ aṣọ, ẹ̀rọ abánáṣiṣẹ́ kan tó lò kùrukùru omi láti lọ aṣọ, s. Passadeira a vapor. Uma máquina elétrica que usa vapor para passar roupas.

Èlò táa fi ń dáhò sí nǹkan, ẹ̀rọ ìdá-nǹkan-lu, s. Furadeira.

Ẹ̀rọ kan tí ó lè gún, s. Uma máquina que pode perfurar, furadeira.

Àwọn ẹ̀rọ tí wọ́n fi ń wa epo jáde látinú ilẹ̀ lónìí, s. Aparelhagem de perfuração moderna.

Ẹ̀rọ tí ó rì, s, Perfuratriz.

Àwọn ayùn ayára bí àṣá tó ń lo iná mànàmáná, s. Serras elétricas de alta velocidade.

Ayùn tó ń lo iná mànàmáná, s. Serra elétrica.

Ayùn ìrẹ́gi, s. Motosserra. 

Ayùn ìrẹ́gi tó ń lo epo mọ́tò, s. Motosserra movida a gasolina.

Ẹ̀rọ ìfabọ́, s. Lavadora de louça automática.

Ẹ̀rọ ìfọbọ́, ẹ̀rọ tó fọ abọ́s. Lavadora de louça.

Ẹ̀rọ tó lè fọ, s. Máquina de lavar. 

Ẹ̀rọ ńlá láti kó àwọn àwókù náà, s. Máquina pesada para limpar os escombros. 

Ẹ̀rọ tí wọ́n fi ń gbálẹ̀, ẹ̀rọ gbálẹ̀ ilé , s. Aspirador de pó.

Maṣíìnì ìránṣọ, maṣín-ìnnì ìránṣọ, ẹ̀rọ ìránṣọ, s.  Máquina de costura.

Fáàànù, ẹ̀rọ àfimí, abẹ̀bẹ̀, s. Ventilador.

Ẹ̀rọ amúlétutù, s. Ar-condicionado.

Ẹ̀rọ ìkọrin àti gbohùngbohùn, s. Amplificador e alto-falante

Ẹ̀rọ gbohùngbohùn, s. Alto-falante.

Makirofóònù, s. Microfone.

Rédíò ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́, s. Autorrádio.

Eré ìdárayá orí kọ̀ǹpútà, s.  Jogos de computador.

Ẹ̀rọ kékeré tá a fi ń wo fídíò, s. Aparelho de DVD portátil.

Fídíò lórí àwo DVD, s. Vídeo em DVD.

Àwo fídíò alodíjítà, s. Disco de vídeo digital, DVD.

Ẹ̀rọ DVD, s. Aparelho de DVD. 

Ẹ̀rọ rẹ́kọ́ọ̀dù, ẹ̀rọ orin aláwo, s. Vitrola.

Giramọfóònù, s. Fonógrafo.

Ẹ̀rọ gbohùngbohùn, ẹ̀rọ ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́, s. Caixa acústica, caixa de som.

Ẹ̀rọ tó gẹrun, ẹ̀rọ tó gẹ irun, s. Máquina de cortar cabelo, cortador de cabelos.

Àwọn ìfárùngbọ̀n tí ń lo iná mànàmáná, s. Barbeadores elétricos.

Ẹ̀rọ tó gé irun imú, s. Aparador de bigode.

Àtẹ bọ́tìnnì onífunra sí ìfọwọ́kàn, s. Teclado de toque.

Àtẹ bọ́tìnnì, s. Teclado. 

Àwọn òòlù àpótíi bọ́tìnnì, s.  Martelos de teclado, martelos de caixa de botão.

Gìtá, s. Violão, guitarra. 

Gòjé, s. Violino, alaúde, viola. 

Móló, bóló, s. Violão hauçá. 

Ohun èlò ìkọrin olókùn tín-ín-rín, s. Instrumento de cordas.

Lírè, s. Lira.

Háàpù, s. Harpa.

Mandolin, s. Bandolim. 

Gòjé-olóhùn, s. Violoncello, cello.

Ọwọ́ ìlẹ̀kùn, s. Maçaneta.

Rìmóòtù, s. Controle remoto.

Ẹ̀rọ ìsanwó, s. Máquina de pagamento.

Ẹ̀rọ ìsanwó-gbowó adáṣiṣẹ́, ẹ̀rọ tó ń gbowó tó sì ń sanwó ní báńkì (ATMs), s. Máquina de pagamento automatizada, caixa eletrônico.

Ohun èlò alágbèéká tó ń ṣiṣẹ́ bíi kọ̀ǹpútà, ẹ̀rọ tablet, s. Tablet, dispositivo portátil que funciona como computador.

Ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ tí ń gbóhùn sáfẹ́fẹ́, s. Carro de som.

Kẹ̀kẹ́ ẹlẹ́sẹ̀ mẹ́ta, s. Triciclo.

Kẹ̀kẹ́ ọmọdé, s. Carrinho.

Kẹ̀kẹ́ tí wọ́n fi ń ti àwọn ọmọ ọwọ́ kiri, kẹ̀kẹ́ téèyàn fi ń ti ọmọ ọwọ́ káàkiri, kẹ̀kẹ́ ọmọdé, s. Carrinho de bebê.

Kẹ̀kẹ́ onígi tí wọ́n fi ń ti ẹrù, s. Chukudu. Uma espécie de patinete artesanal de madeira para transportar cargas.

Akoto tí mo máa ń dé lórí alùpùpù, s. Capacete de moto.

Mọtosááikù, alùpùpù, s. Motocicleta, moto. 

Ọkọ̀ orí yìnyín, s. Moto de neve.

Alùpùpù tí ọmọdé ń lò, s. Moto infantil.

Ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ tí ọmọdé ń lò, s. Carro que criança usa.

Básíkùlù, kẹ̀kẹ́, s. Bicicleta.

Ẹ̀rọ àmúdán, s. Enceradeira.

Agbada onírin, s. Frigideira de ferro. A frigideira é uma panela usada pra fritar carnes, batatas, ovos, legumes e outros alimentos.  Agbada, s. Vasilha utilizada para cozinhar ou fritar àkàrà. 

Páànù tí wọ́n fi ń dín nǹkan kaná, s. Frigideira. Páànù, s. Panela, caçarola, prato esmaltado.

Ìhùmọ̀ agbésọfúnni láti ojúde òfuurufú tí ó rí bí ọ̀pá àti ìhùmọ̀ aṣàwárí mẹ́táàlì, s. Sonda parecida com bastão e detector de metais, sonda que se parece com uma haste e um detector de metais.