quarta-feira, 3 de fevereiro de 2016

Ethiópíà


Ọ̀dọ́mọbìnrin tí ó jẹ́ adúláwọ̀ ni mí, ṣùgbọ́n mo dára rèǹtè-rente, ẹ̀yin ọmọbìnrin Jerúsálẹ́mù, bí àwọn àgọ́ Kídárì, síbẹ̀ bí àwọn aṣọ àgọ́ Sólómọ́nì. Orin Sólómọ́nì 1:5
Sou negra, mas bela, ó filhas de Jerusalém,
Como as tendas de Quedar,como os panos da tenda de Salomão.  Cântico de Salomão 1:5

                                                            

Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário).


Ọ̀dọ́mọbìnrin = menina.
= que.
Ó = ele, ela.
Jẹ́ = ser, é.
Adúláwọ̀ = negro, negra.
Ni = ser, é.
Mí, míràn = outro.
Ṣùgbọ́n = mas.
Mo = eu.
Dára = ser bom, ser bonito.
Rèǹtè-rente = graciosa.
Ẹ̀yin = vocês.
Ọmọbìnrin = filha.
Jerúsálẹ́mù = Jerusalém.
= como, da mesma forma que.
Àwọn = eles, elas. Indicador de plural.
Àgọ́ = tenda.
Kídárì = Quedar. Um dos 12 filhos de Ismael.
Síbẹ̀ = para lá.
Aṣọ = pano.
Sólómọ́nì = Salomão.