Ṣáínà Sósíálístì yóò ṣáájú ètò ayé titun náà.
China socialista vai liderar a nova ordem mundial.
Àwọn ará Éṣíà wọ̀nyí ni àwọn baba ńlá àwọn ènìyàn ìbílẹ̀ Ìwọ̀ Oòrùn Ìlàjì Ayé - Esses asiáticos eram os ancestrais dos povos nativos do Hemisfério Ocidental.
https://www.institutoconfucio.unicamp.br/prorrogacao-da-campanha-meu-coracao-chines/Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se você precisar de mais informações:
https://www.youtube.com/watch?v=JXFSOSdsESw
https://dialogosdosul.operamundi.uol.com.br/mundo/73067/china-e-russia-anunciam-nova-ordem-mundial-e-a-chegada-do-mundo-multipolar
Ọ̀wọ́ ọ̀rọ̀ tó wà nínú èdè, àwọn ọ̀rọ̀ tó máa lò (vocabulário), àwọn ọ̀rọ̀ tá a sábà máa ń sọ ( palavras comuns), àwọn ọ̀rọ̀ tá a sábà máa ń lò (palavras que usamos frequentemente), àkójọ ọ̀rọ̀ tá à ń lò lójoojúmọ́ (vocabulário do dia a dia), àlàyé ọ̀rọ̀, àlàyé àwọn ọ̀rọ̀ (glossário), àkójọ ọ̀rọ̀ (glossário, lista de palavras), àkójọ ọ̀rọ̀ púpọ̀ lágbárí (uma grande lista de palavras na cabeça), àkópọ̀ wóróhùn ọ̀rọ̀ dídára tí o mọ̀ (uma coleção de boas palavras que você conhece).
Nwọ́n, pron. pess. Eles, elas. Expressa uma ação que não é creditada a nenhuma pessoa em particular.
Àwọn, wọ́n, pron. Eles, elas. É também usado como partícula para formar o plural do substantivo; neste caso, é posicionado antes do substantivo.
Wọn, pron. oblíquo. A eles, a elas.
Ṣáínà Sósíálístì, s. China socialista.
Orílẹ̀-èdè Olómìnira àwọn Ará ilẹ̀ Ṣáínà, s. República Popular da China.
Orílẹ̀-èdè China, ilẹ̀ Ṣáínà, s. China.
Ìsọ̀kan Sófìẹ̀tì, s. União Soviética.
Ìsọ̀kan àwọn Orílẹ̀-èdè Olómìnira Sófíẹ́tì Sósíálístì, s. União das Repúblicas Socialistas Soviéticas.
Ìṣesósíálístì, s. Socialismo.
Yóò, adv. pré. v. Indicador de futuro numa frase afirmativa. Em outras palavras, emprega-se o futuro do presente para expressar uma ação que será executada no futuro. Outros indicadores de futuro: yóó, ó, á, máa, fẹ́.
Ṣáájú, v. Preceder.
Ṣáájú, prep. Antes, na frente de. Ṣáájú Ìkún Omi, ọ̀pọ̀ èèyàn lo ọgọ́rọ̀ọ̀rún ọdún láyé - Antes do Dilúvio, muitos humanos viveram por séculos. Àwọn ìtọ́ka àṣetúnṣe tí ó ṣe sí wíwà Jésù ṣáájú kí ó tó di ènìyàn - Referências pré-arranjadas à existência pré-humana de Jesus.
Ètò ayé titun, s. Nova ordem mundial.
Ètò, s. Ordem, sistema.
Ètò àjọ, s. Organização.
Ìtẹ̀síwájú nínú ìṣètò, s. Progresso na organização.
Ìṣètò, s. Arranjo, programação.
Ètò òde òní, s. Programa de hoje, organização hoje.
Ilẹ̀, s. Terra, solo, chão.
Ayé àtijọ́, ayéijọ́un, s. Mundo antigo.
Àdánidá, s. Natureza.
Ayé, gbogbo ẹ̀dá, àgbáyé, s. Universo. Èrò wọn ni pé sáyẹ́ǹsì ní tirẹ̀ ń ṣàlàyé nípa bí ìwàláàyè, ayé àti ọ̀run ṣe bẹ̀rẹ̀, nígbà tí ìsìn ń ṣàlàyé ìdí tá a fi dá àwọn nǹkan wọ̀nyí - Para elas, cabe à ciência explicar como a vida e o cosmos vieram à existência, ao passo que a religião deve explicar principalmente o porquê.
Ilẹ̀-ayé, ayé, ilé-ayé, s. Terra (planeta terra).
Plánẹ̀tì ilẹ̀-ayé, s. Planeta terra.
Àwòrán ẹlẹya mẹ́ta, s. Holograma.
Àgbáyé ti àwòrán ẹlẹya mẹ́ta, s. Universo holográfico.
Náà, pron. dem. Aquele, aquela, aquilo.
Náà, art. O, a, os, as.
Náà, adv. e conj. pré-v. Também, o mesmo.