Tẹ́lí-ẹ̀kọ́ (telecurso)
Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.
sexta-feira, 29 de abril de 2016
Vídeos sobre física quântica
Àwọn fídíò lórí físíksì kúántù.
Vídeos sobre física quântica.
Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀ (Vocabulário).
Àwọn, wọn, pron. Eles, elas. Indicador de plural.
Fídíò, fídéò, s. Vídeo.
Lórí, lérí, prep. Sobre, em cima de.
Ìmòye, filọ́sọ́fi, s. Filosofia.
Sáyẹ́nsì, s. Ciência.
Físíksì, s. Física.
Ìmọ̀ìràwọ̀títò, s. Astronomia.
Ìmọ̀ìdáyé, s. Cosmologia.
Àdánidá, s. Natureza.
Èlò, s. Matéria.
Ìṣiṣẹ́ẹ̀rọ, s. Mecânica.
kùátọ̀mù, kúántù, adj. Quântico.
Ìṣiṣẹ́ẹ̀rọ kùátọ̀mù, ìṣiṣẹ́ẹ̀rọ kúántù, s. Mecânica quântica.
Vídeos sobre física quântica.
Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀ (Vocabulário).
Àwọn, wọn, pron. Eles, elas. Indicador de plural.
Fídíò, fídéò, s. Vídeo.
Lórí, lérí, prep. Sobre, em cima de.
Ìmòye, filọ́sọ́fi, s. Filosofia.
Sáyẹ́nsì, s. Ciência.
Físíksì, s. Física.
Ìmọ̀ìràwọ̀títò, s. Astronomia.
Ìmọ̀ìdáyé, s. Cosmologia.
Àdánidá, s. Natureza.
Èlò, s. Matéria.
Ìṣiṣẹ́ẹ̀rọ, s. Mecânica.
kùátọ̀mù, kúántù, adj. Quântico.
Ìṣiṣẹ́ẹ̀rọ kùátọ̀mù, ìṣiṣẹ́ẹ̀rọ kúántù, s. Mecânica quântica.
Assinar:
Postagens (Atom)