domingo, 16 de maio de 2021

Sonda espacial chinesa pousa em Marte.

Ẹ̀rọ atàtaré ìsọfúnni láti gbalasa òfuurufú ilẹ̀ Ṣáínà gúnlẹ̀ sórí Mársì.

Sonda espacial chinesa pousa em Marte.



Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se você precisar de mais informações:


https://www.cnnbrasil.com.br/tecnologia/2021/05/15/nave-espacial-chinesa-pousa-em-marte-veja-momento-exato

Ọ̀wọ́ ọ̀rọ̀ tó wà nínú èdè, àwọn ọ̀rọ̀ tó máa lò, àkójọ ọ̀rọ̀ tí òń lò lójoojúmọ́, àwọn àkànlò ọ̀rọ̀, àwọn àkànlò èdè, ọ̀rọ̀ tó máa ń sọ, àkànlò èdè lọ́nà tó gún régé (vocabulário).


Nwọ́n, pron. pess. Eles, elas. Expressa uma ação que não é creditada a nenhuma pessoa em particular.

Àwọn, wọ́n, pron. Eles, elas. É também usado como partícula para formar o plural do substantivo; neste caso, é posicionado antes do substantivo.

Wọn, pron. oblíquo. A eles, a elas.

Wọn, pron. poss. Deles, delas.

Ẹ̀rọ rọ́bọ́tì, ère tí ẹ̀rọ nmú rìn, rọ́bọ́tì, rọ́bọ́ọ̀tì, s. Robô.

Rọ́bọ́ọ̀tì ilẹ̀ Ṣáínà, s. Robô chinês.

Ilẹ̀ Ṣáínà, s. China.

Orílẹ̀-èdè Olómìnira àwọn Ará ilẹ̀ Ṣáínà, s. República Popular da China.

Gúnlẹ̀, v. Pousar.

Balẹ̀, v. Tocar o solo, descer, desmontar.

Nípa, nípasẹ̀, adv. Sobre, acerca de, concernente a.
Kọjá, prep. Sobre, além de. 
Ní orí, lórí, lérí, prep. Sobre, em cima de, cerca de, acerca de, a respeito de. 
Lórísórí, prep. Em, por, ao. sobre. 
Sórí, prep. Para cima de. 
Nípati, prep. Conforme. 
Lókè, ní òkè, prep. Acima, no alto de.

Mársì, s. Marte. 

Rìn lórí pílánẹ́ẹ̀tì Máàsì, v. Andar na face do planeta Marte, andar sobre Marte.

Ṣàyẹ̀wò erùpẹ̀ pílánẹ́ẹ̀tì kan tó ń jẹ́ Máàsì, v. Examinar o solo do planeta Marte.

Àwọn arìnrìn-àjò sánmà, s. Astronautas, cosmonautas, taiconautas, afronautas.

Arìnlófurufú, arìnrìn-àjò ní ojúde òfuurufú, arìnrìn-àjò ní gbalasa òfuurufú, s. Astronauta, cosmonauta, taikonauta, afronauta. 

Ọkọ̀ àgbéresánmà kan tó máa ń rìn àjò lọ sínú gbalasa òfuurufú, s. Uma sonda espacial que viaja pelo espaço.

Ọkọ̀ àgbéresánmà, s. Nave espacial.

Ọkọ̀ ìṣèwádìí gbalasa òfuurufú, ẹ̀rọ atàtaré ìsọfúnni láti gbalasa òfuurufú, ọkọ̀ tí a fi ń ṣewádìíkiri gbangba òfuurufú, s. Sonda espacial. 

Ìwákiri lófurufú, s. Exploração espacial. 
Ọkọ̀ òfurufú, s. Avião
Ọkọ̀, s. Canoa, veículo, carro.

Ọkọ̀-àlọbọ̀ Òfurufú, Ọkọ̀-ayára Òfurufú, s. Ônibus espacial.

Ìrìnlófurufú, s. Aeronáutica.

Òfurufú, òfuurufú, ojú òfurufú, inú òfurufú, s. Espaço sideral.

Gbalasa, adj. Amplo, vasto (usado com relação a água).

Ilé-iṣẹ́ Àgbéṣe Ìgbédìde àti Ìwáàdí Òfurufú Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, s. National Space Research and Development Agency (NASRDA). Agência Nacional de Pesquisa e Desenvolvimento Espacial (NASRDA) é o nacional agência espacial do Nigéria.

Rọ́kẹ́ẹ̀tì, s. Foguete.

Àwọn ìtànṣán gbalasa òfuurufú tàbí ti olóró gíga, s. Raios gama ou cósmicos.

Ibi ìbalẹ̀sí tàbí ibi ìgbérafò lójú òṣùpá, s. Alunissagens ou bases na lua. A alunissagem ou alunagem consiste no ato de pousar uma nave espacial na Lua. Incluem-se nesta categoria tanto os pousos tripulados quanto não tripulados (missões robóticas).