quarta-feira, 6 de janeiro de 2021

Homens-bomba

 Àwọn oníbọ́ǹbù apara-ẹni-mọ́-ọ̀tá (homens-bomba).



Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se você precisar de mais informações:

https://www.infoescola.com/noticias/infoatualidades-o-que-sao-e-como-surgiram-os-homens-bomba/


Ọ̀wọ́ ọ̀rọ̀ tó wà nínú èdè, àwọn ọ̀rọ̀ tó máa lò, àkójọ ọ̀rọ̀ tí ò ń lò lójoojúmọ́, àwọn àkànlò ọ̀rọ̀, àwọn àkànlò èdè, ọ̀rọ̀ tó máa ń sọ, àkànlò èdè lọ́nà tó gún régé (vocabulário).


Nwọ́n, pron. pess. Eles, elas. Expressa uma ação que não é creditada a nenhuma pessoa em particular.

Àwọn, wọ́n, pron. Eles, elas. É também usado como partícula para formar o plural do substantivo; neste caso, é posicionado antes do substantivo.

Wọn, pron. oblíquo. A eles, a elas.

Wọn, pron. poss. Deles, delas.

Oníbọ́ǹbù apara-ẹni-mọ́-ọ̀tá, s. Homem-bomba. Àwọn agbawèrèmẹ́sìn tí wọ́n ṣe tán láti pa ara wọn nígbà tí wọ́n ba ń pa àwọn tí wọ́n kà sí alátakò wọn - Extremistas religiosos que explodem a si mesmos ao passo que matam seus supostos inimigos.

Ẹ̀fúùfù láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run, ẹ̀fúùfù látọ̀dọ̀ Ọlọ́run, s. Vento divino (camicase, kamikaze). 

Mẹ́ḿbà ẹgbẹ́ ọmọ ogun afọkọ̀ òfúúrufú jagun, s.  Membro da força de ataque camicase.

Awakọ̀ òfúúrufú tí a fi ń jagun ṣe fún orílẹ̀-èdè àti olú-ọba rẹ̀, s. Piloto camicase para uma nação e seu imperador.

Ológun òfuurufú ilẹ̀ Jèpánù nígbà Ogun Àgbáyé Kejì, s. Camicase japonês na Segunda Guerra Mundial.

Ìpániláyà kan tó ń gbẹ̀mí àwọn èèyàn rẹpẹtẹ, s. Um ataque terrorista que mata muitas pessoas, ataque suicida.

Àmùrè kan tó ní àwọn bọ́ǹbù, bẹ́líìtì tó ní àwọn bọ́ǹbù, s. Cinturão-bomba.