segunda-feira, 3 de julho de 2017

Orin

Aṣa - Ẹyẹ Àdàbà - pẹ̀lú àkọlékè. 
Asha - Pomba - Legendada. 

                                                        




Ẹyẹ Àdàbà
Canção de Aṣa
Letra

Ojúmọ́ ti mọ, ojúmọ́ ti m mi
Ní ilẹ̀ yí o
Ojúmọ́ ti mọ, mo rí 're o
Ojúmọ́ ti mọ, ojúmọ́ ti m mi
Ní ilẹ̀ yí o
Ojúmọ́ ti mọ, mo rí 're o
Ẹyẹ àdàbà, ẹy àdàbà
Ẹyẹ àdàbà tí fò l'ókè l'ókè
Wá a bà lé mi o o
Ojúmọ́ ti mọ, mo rí 're o
Ojúmọ́ ti mọ, ojúmọ́ ti m mi
Ní ilẹ̀ yí o
Ojúmọ́ ti mọ, mo rí 're o
Ojúmọ́ ti mọ, ojúmọ́ ti m mi
Ní ilẹ̀ yí o
Ojúmọ́ ti mọ, mo rí 're o, ó yá
Ẹyẹ àdàbà, ẹyẹ àdàbà, ẹyẹ e e e
Ẹyẹ àdàbà tí fò l'ókè l'ókè
Wá a bà lé mi o o
Ojúmọ́ ti mọ, mo rí 're o, ó yá
Ẹyẹ àdàbà, ẹyẹ àdàbà, ẹyẹ e e e
Ẹyẹ àdàbà tí fò ó ń fò ń fò
Wá a bà lé mi o o
Ojúmọ́ ti mọ, mo rí 're o
Ẹ wí kí n gbọ́ sẹ́
Ẹyẹ àdàbà, ẹyẹ eee
Ẹyẹ àdàbà tí fò l'ókè l'ókè l'ókè ó dé ọ̀run
Wá bà lé mi o o
Ojúmọ́ ti mọ, mo rí 're o
O o o ó yè e
Ẹyẹ àdàbà, ẹyẹ àdàbà, ẹyẹ o o
Ẹyẹ àdàbà tí fò ó ń fò ń fò
Wá bà lé mi o o
Ojúmọ́ ti mọ, mo rí 're o
O o oo oo ooo
O o oo o
Ẹ wí kí n gbọ́ sẹ́
O o oo o
Aah o o o oo o
Oo mo rí 're o
O o o o ooo o
Mo rí 're o
Ire ire ire ooo
O o o o o
Mo rí 're o
Ẹyẹ àdàbà, ẹyẹ àdàbà
Ẹyẹ tí fò l'ókè l'ókè ó dé ọ̀run
Wá bà lé mi o o
Ojúmọ́ ti mọ, mo rí 're o


Compositores: Bukola Elemide / Cobhams Emmanuel Asuquo
Letra de Eyé Àdabá © Sony/ATV Music Publishing LLC




Colorismo

                                                         
Ìyàsọ́tọ̀  nípa àwọ̀ ti awọ ara.
Pigmentocracia, colorismo (discriminação pela cor da pele).







Neste didático TEDx, a mestranda Chika Okoro, da universidade de Stanford, explica o que é, da onde veio e quais são os efeitos do colorismo na mente e na sociedade. 


Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário).

Yíyanípa, ìyàsápákan, ìyàsọ́tọ̀, ìpínyà, s. Separação, discriminação.
Nípa èyí, adv. Pelo seguinte.
Nípa, nípasẹ̀, adv. Sobre, acerca de, concernente a.  
Àwọ̀, s. Cor.
Ti, prep. de ( indicando posse). Quando usado entre dois substantivos, usualmente é omitido. Ilé ti bàbá mi = ilé bàbá mi ( A casa do meu pai).
Ara, s. Corpo, membro, substância, troco.
Èèpo, s. Palha, casca, pele, vagem, concha.
Awọ ara, s. Pele.
Awọ, s. Pele humana ou de animal, pelo.