quarta-feira, 20 de junho de 2018

Renato Noguera

Ohùn àfetígbọ́ lórí ìmọ̀ ọgbọ́n orí àwọn ọmọ ilẹ̀ Áfíríkà.
Áudio sobre filosofia africana.
                                                          



Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário).

Fídíò, fídéò, s. Vídeo.
Ohùn àfetígbọ́, s. Áudio. Bákan náà, wọ́n kọ́ yàrá ìgbóhùn sílẹ̀ fún ẹ̀ka tó ń gba ohùn àti àwòrán sílẹ̀ àti ẹ̀ka tó ń bójú tó Èdè Adití, wọ́n sì dá ẹ̀ka tó ń ṣe ìwé àwọn afọ́jú sílẹ̀ - Além disso, o Áudio e Vídeo e a Língua de Sinais ganharam novos estúdios, e foi iniciada a transcrição para o braile.
Ìtẹ̀jáde tá a gbohùn, s. Publicação de Áudio 
Àwọn ìtẹ̀jáde tá a gbohùn wọn sílẹ̀, s. Publicações em áudio.
Fífi ariwo rédíò ọkọ̀ díje, s. Rachas” de áudio.
Pípo ohùn pọ̀, s. Mixagem de áudio.
Ohùn tá a gbà sílẹ̀ sórí kásẹ́ẹ̀tì, s. Gravação de áudio. Lára wọn ni àwọn ìwé, ìwé ìròyìn, ìwé pẹlẹbẹ, ìwé ìléwọ́, ìwé àṣàrò kúkúrú, ohùn tá a gbà sílẹ̀ sórí kásẹ́ẹ̀tì àti fídíò - Essas incluem livros, revistas, brochuras, convites, tratados e gravações de áudio e vídeo.
Mílíọ̀nù méjìlélógún, num. 22 milhões.  Mílíọ̀nù méjìlélógún ohun àtẹ́tígbọ́ - 22 milhões de faixas de áudio.
Filọ́sọ́fi ti Áfríkà, ìmọ̀ ọgbọ́n orí àwọn ọmọ ilẹ̀ Áfíríkà, s. Filosofia africana.
Ìmọ̀ ọgbọ́n orí àwọn Gíríìkì, s. Filosofia grega.
 Ìwé àpókírífà, s. Livro apócrifo.
Ẹ̀kọ́ ojoojúmọ́, s. Ensino diário.
Ẹsẹ Ìwé Mímọ́, s. Texto bíblico.
Ìjíròrò ẹ̀kọ́ ojoojúmọ́, s. Considerações do texto diário, discussão do texto, discussão diária.
Ìwé tó kọ, s. Escrito.
Nípa, nípasẹ̀, adv. Sobre, acerca de, concernente a.
Kọjá, prep. Sobre, além de. 
Ní orí, lórí, lérí, prep. Sobre, em cima de, cerca de, acerca de, a respeito de. Níbi Àpérò Ìjọba Lórí Híhùwà Ipá sí Àwọn Obìnrin, èyí tó wáyé ní orílẹ̀-èdè Sípéènì ní ìbẹ̀rẹ̀ ọdún 2002 -  No Congresso Ministerial sobre a Violência contra as Mulheres, realizado na Espanha no início do ano de2002
Lórísórí, prep. Em, por, ao. sobre. 
Sórí, prep. Para cima de. 
Nípati, prep. Conforme. 
Lókè, ní òkè, prep. Acima, no alto de.
Áfríkà, Áfíríkà, s. África.

Ọgbọ́n, s. Sabedoria, senso, arte.
Ìmọ̀, s. cultura, saber. conhecimento.
Ìjìnlẹ̀, s. Profundidade, intensidade.

Sáyẹ́nsì, ìmọ̀ ìjìnlẹ̀, s. Ciência.
Orí, s. Cabeça.
Àwọn, wọ́n, pron. pess. Eles, elas. Indicador de plural.
Wọn, pron. oblíquo. A eles, a elas.
Wọn, pron. poss. Deles, delas.

Ọmọorílẹ̀-èdè Bràsíl, ọmọ ilẹ̀ Bràsíl, ọmọkùnrin ilẹ̀ Bràsíl, s. Brasileiro.
Ọmọkùnrin ilẹ̀ Bràsíl, s. Brasileiro do sexo masculino.
Ọmọbìnrin ilẹ̀ Bràsíl, s. Brasileira.
Ní ti Bràsíl, ti orílẹ̀ èdè Bràsíl, adj. Brasileiro.

Àwọn ará, s. Parentes, irmãos, habitantes de uma região (irmandade, popular). Orílẹ̀-èdè Olómìnira àwọn Ará ilẹ̀ Ṣáínà - República Popular da China.

Àwọn adúláwọ̀ ti ẹgbẹ́ aláṣẹ bóofẹ́bóokọ̀ ní'lẹ̀ Bràsíl, s. Negros de extrema direita no Brasil.
Ọmọ Áfíríkà Bòlífíà, s. Afroboliviano.
Ọmọkùnrin Áfíríkà Bòlífíà, s. Homem afroboliviano.
Ọmọbìnrin Áfíríkà Bòlífíà, s. Mulher afroboliviana.

Ní ti Áfríkà, ti orílẹ̀ èdè Áfríkà, adj. Africano.
Ọmọ ilẹ̀ Áfríkà, s. Africano.
Ọmọ kùnrin ilẹ̀ Áfríkà, s. Africano.
Ọmọbìnrin ilẹ̀ Áfríkà, s. Africana.
Ọmọ Áfríkà Amẹ́ríkà, aláwọ̀dúdú Ará Amẹ́ríkà, adúláwọ̀ ará Amẹ́ríkà, s. Afro-americano.
Ọmọ Áfríkà Ásíà, s. Afro-asiático.
Ọmọ Áfríkà Bràsíl, aláwọ̀dúdú ará Bràsíl, adúláwọ̀ ará Bràsíl, s. Afro-brasileiro.
Ọmọ Áfríkà Kàríbẹ́ánì, aláwọ̀dúdú ará Kàríbẹ́ánì, adúláwọ̀ ará Kàríbẹ́ánì, s. Afro-caribenho.
Ọmọ Áfríkà Kúbà, aláwọ̀dúdú ará Kúbà, adúláwọ̀ ará Kúbà, s. Afro-cubano.
Melanésíà, s. Melanésia.
Papua, s. Papua.
mọorílẹ̀-èdè papua, s. Papuásio. Natural de Papua-Nova Guiné.
Ní ti papua, adj. Papuásio. Relativo a Papua-Nova Guiné.
Ní ti Melanésia, adj. Melanésio.
Ọmọ ilẹ̀ Melanésia, s. Melanésio.
Ẹ̀yà ènìyàn tàmil, s. Etnia tâmil.
Ní ti tàmil, adj. Tâmil.
Ọmọ ilẹ̀ Tàmil Nadu, s. Tâmil.
Ọmọ ilẹ̀ Éṣíà dúdú, s. Asiático negro.
Ọmọorílẹ̀-èdè Íńdíà dúdú, s. Indiano negro.

Aláwọ̀funfun, s. Branco.
Òyìnbó, òyìbó, òìbó, s. O homem branco, o europeu.
Funfun, adj. Branco.

Ilẹ̀, s. Terra, solo, chão.
Ilẹ̀ Bràsíl, Bràsíl, s. Brasil, Pindorama.
Orílẹ̀-èdè Olómìnira Aparapọ̀ ilẹ̀ Bràsíl, s. República Federativa do Brasil.
Orílẹ̀-èdè, s. Nação, país.
Orílẹ̀, s. Grupo de origem ou clã.
Èdè, s. Língua, idioma, dialeto, linguagem.
Olómìnira, adj. Independente.
Àpapọ̀, s. Soma, total, combinação, ato de unir, de juntar
Aparapọ̀, adj. Federativa. 

Ẹlẹ́yàpúpọ̀, s. Indivíduo mestiço, colorido ou multirracial.
Adúláwọ̀, s. Negro.

Ènìyàn dúdú, s. Negro.
Dúdú, v. Ser preto.
Dúdú, adj. Negro.
Adúláwọ̀ ọkàn funfun, s. Negro de alma branca, negropeu, negro jabuticaba (preto por fora e branco por dentro).
Ẹ̀mí, s. Alma (vida representada pela respiração).
Yúróòpù, Yúrópù, s. Europa.

Ọ̀mọ̀, s.Uma árvore cuja madeira é utilizada para fazer o tambor bẹ̀mbẹ́. Cordia millenii (Boraginaceae).
Ọmọ, s. Filho, criança, descendência.
Ọmọbìnrin, s. Filha.
Ọmọkùnrin, s. Filho. 
Ọmọ àgbàbọ́, s. Filho adotivo.

Ọmọ àgbo, ọmọ ọwọ́, ọmọ ọmú, s. Bebê, criança.
Ọmọ aládé, s. Príncipe, princesa.
Ọmọ aláìloobiọmọ òkús. Órfão.
Ọmọ àlè, s. Bastardo, o filho da outra.
Ọmọbíbí, s. Nascimento de uma criança.
Ọmọdé, s. Criança.
Ọmọ̀dọ̀, s. Criada, serviçal.
Ọmọdọ́mọ, s. De criança em criança, de tempos em tempos.
Ọmọ ènìà, s. Ser humano, cavalheiro.
Ọmọ ẹ̀hìn, s. Discípulo, seguidor, aprendiz.
Ọmọge, s. Mulher jovem, criada.
Ọmọge ìbílẹ̀, mọ ìlú, s. Nativo da terra.
Ọmọ iléwé, akẹ́kọ̀ọ́, akẹ́kọ́, ọmọ ilé-ẹ̀kọ́, ọmọ-sùkúrùs. Aluno, estudante.
Ọmọ ìlú, s. Nativo da mesma cidade, nativo da mesma região.
Ọmọ jẹ́jẹ́, s. Criança fina, gentil.
Ọmọkọ́mọ, s. Qualquer criança, uma criança má.
Ọmọ làlà, s. O primeiro neto.
Ọmọlé, s. Grupo familiar.
Ọmọlẹ́hìn, s. Seguidor.
Ọmọlójú, s. Neto, menina dos olhos.
Ọmọlúwàbí, s. Pessoa de caráter, cavalheiro e educado.
Ọmọ ọba, s. Filho do rei, príncipe, princesa.
Ọmọnìkéjì, s. Companheiro, vizinho.
Ọmọ mọ, s. Neto.
Ọmọ-ọmú, s. Criança em fase de amamentação.
Ọmọpẹ́, s. Denominação de uma criança que passa dos nove meses de gestação.
Ọmọṣẹ́, s. Aprendiz de trabalho.
Ọmọ tuntun, s. Recém-nascido, bebê.
Ọmọ wáhàrí, s. Filho de uma escrava tomada como esposa.
Ọ̀mọ̀wé, s. Pessoa educada, sábia.
Ọ̀mọwẹ̀, s. Nadador.


Ìlómìnira látọwọ́ Pọ́rtúgàl, s. Independência de Portugal.


Marilena Chaui

 Àwùjọ abàṣẹwàá, ìwàwíwù àti ìwà ipá ní orílẹ̀-èdè Bràsíl.
Sociedade autoritária, ética e violência no Brasil.                                             




Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário).

Àròjinlẹ̀ aláyẹ̀wò, s. Teoria crítica da sociedade.
Ìṣeọ̀rọ̀àwùjọ, s. Sociologia.
Abàṣẹwàá, apàṣẹwàá, s. Ditador. Ṣé apàṣẹwàá ni bàbá rẹ̀ tó fi jẹ́ pé ohun tó bá sọ pé kó ṣe ló gbọ́dọ̀ ṣe? - Podia contrariar a vontade do pai autoritário?
Ìjọba bóofẹ́-bóokọ̀, ìṣàkóso abàṣẹwàá, s. Ditadura. 
Òṣèlúaráìlú, ìjọba tiwa-n-tiwa, ìjọba àjùmọ̀ṣe, ìjọba tí ó fi àyè gba ará ìlú láti ní ìpín nínú ètò ìlú, s. Democracia.
Ìjọba àjùmọ̀ṣe, s.Governo de ação conjunta, governo de parceria.
Ìjọba tí ó fi àyè gba ará ìlú láti ní ìpín nínú ètò ìlú, s. Governo que permite e necessita que os cidadãos tenham parte na organização da cidade ou do país. 
Òṣèlúaráìlú òṣèlú aṣojú, s. Democracia representativa.
Orílẹ̀-èdè olómìnira, s. República.
Òṣèlú aláwùjọ, s. Social-democracia.
Àjọṣepọ̀, s. Federação.
Ìṣeolómìnira ijọ́hun, s. Republicanismo clássico.
Ọ̀làjú, s. Iluminismo, civilização.
Àwọn ọ̀tọ̀kùlú, s. Os nobres, aristocracia.
Àwọn sàràkí-sàràkí, àwọn ọ̀tọ̀kùlú, àwọn èèyàn jàǹkànjàǹkàn, s. Aristocracia. Àwọn sàràkí-sàràkí ìlú Jerúsálẹ́mù fẹ̀sùn kàn án pé ńṣe ló fèrú gba ipò, wọ́n sì rọ ìjọba Róòmù láti rọ̀ ọ́ lóyè - A aristocracia de Jerusalém considerava Herodes um usurpador e tentou convencer Roma a destituí-lo.
Àwùjọ, s. Sociedade.
Àwùjọ abàṣẹwàá, s. Sociedade autoritária.
Ìlànà lórí omi lílò, s. Ética da água.
Ọ̀fin, s. Lei, estatuto.
Ìwàwíwù, ìwà, ẹ̀kọ́ ìwà rere, s. Ética.
Ìwà, s.  Conduta, caráter, comportamento.
Ìwàrere, s. Boa conduta, um bom caráter.
Ẹ̀kọ́, s.  Aula, educação, instrução.
Wíwù, ẹwù, s. Prazer, agradabilidade.

Àwọn ọmọ tí òbí wọn bá ń fi ìfẹ́ bá wí, s. Filhos de pais que conseguem equilibrar o amor com a disciplina.
Ìwà ipá, s. Violência. Kí ló ń fa ìwà ipá yìí? - O que causa essa violência?
Ilẹ̀, s. Terra, solo, chão.
Orílẹ̀-èdè BràsílIlẹ̀ Bràsíl, Bràsíl, s. Brasil, Pindorama.
Orílẹ̀-èdè Olómìnira Aparapọ̀ ilẹ̀ Bràsíl, s. República Federativa do Brasil.
Orílẹ̀-èdè, s. Nação, país.
Orílẹ̀, s. Grupo de origem ou clã.
Èdè, s. Língua, idioma, dialeto, linguagem.
Olómìnira, adj. Independente.
Àpapọ̀, s. Soma, total, combinação, ato de unir, de juntar
Aparapọ̀, adj. Federativa.
Ọmọorílẹ̀-èdè Bràsíl, ọmọ ilẹ̀ Bràsíl, ọmọkùnrin ilẹ̀ Bràsíl, s. Brasileiro.
Ọmọkùnrin ilẹ̀ Bràsíl, s. Brasileiro do sexo masculino.
Ọmọbìnrin ilẹ̀ Bràsíl, s. Brasileira.

Ní ti Bràsíl, ti orílẹ̀ èdè Bràsíl, adj. Brasileiro. 
Orílẹ̀-Èdè Rússíà, Rọ́síà, s. Rússia.
Ìparapọ̀ Rọ́sìà, s. Federação Russa.

Ń, v. Estar. Indicador de  gerúndio.
Ń, adv. pré-verbal. O prefixo "ń" no verbo indica não só uma ideia presente como uma ação que esteja ocorrendo, em desenvolvimento (gerúndio). Pela sua função, é equivalente ao verbo auxiliar estar em português.
L', pref. No.
L, pref. Forma modificada da palavra ní quando seguida de palavra iniciada por vogal diferente de i.
, prep. Contração da preposição ní e substantivo. Quando a vogal inicial do substantivo não é i, a consoante n da preposição se transforma em l, e a vogal i toma forma de vogal do substantivo posterior. Mas se a vogal do substantivo é i, ela é eliminada. Ní àná ( l'ánàá ). Ní ilé (ní'lé)
, part. enfática. Usada na construção de frases, quando o verbo tiver dois objetos, o segundo objeto é precedido por " ní".
, prep. No, na, em. Usada para indicar o lugar em que alguma coisa está. Indica uma posição estática.
, v. Ter, possuir, dizer.Transportar carga em um barco ou navio. Ocupar, obter, pegar.
Ni, v. Ser, é.
, pron. dem. Aquele, aquela. Requer alongamento da vogal final da palavra que o antecede somente na fala. Ex.: Fìlà ( a ) nì = aquele chapéu.

, ( conj. pré-v.). E, além disso, também. Liga sentenças, porém, não liga substantivos; nesse caso, usar " àti". É posicionado depois do sujeito e antes do verbo.
Ti, àti, conj. E.
Àti, Conj. E. Usada entre dois nomes, mas não liga verbos. 
Pẹ̀lú, conj. E. Liga substantivos, mas não liga verbos.
Pẹ̀lú, prep. Com, junto com.
Pẹ̀lú, adv. Também.
Pẹ̀lú, v. Estar em companhia de, acompanhar.
Òun, ó, pron. pess. Ele, ela.
Òun, on, Conj. E. Geralmente usada com nomes de pessoas. Òjó on Àjàdí - Ojô e Ajadi.
Oun, ohun, s. Coisa, algo.
Oùn, ohùn, s. Voz.